Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Ìgbàgbọ́ Nínú Ọlọ́run

gbàgbọ́ jẹ́ ohun tó lágbára gan-an tó lè mú káyé ẹni dára. Ó lè jẹ́ kó o ní ìbàlẹ̀ ọkàn ní báyìí, kó o sì tún ní ìrètí tó dájú fún ọjọ́ ọ̀la. Bóyá o kò gba Ọlọ́run gbọ́ ní o, àbí oò nígbàgbọ́ bíi ti tẹ̀lẹ́ mọ́, tàbí kẹ̀, tóo bá fẹ́ kí ìgbàgbọ́ rẹ túbọ̀ lágbára sí i, Bíbélì lè ràn ẹ́ lọ́wọ́.

TẸ̀ LÉ ÀPẸẸRẸ ÌGBÀGBỌ́ WỌN

Míríámù—“Ẹ Kọrin sí Jèhófà”!

Ọlọ́run mí sí wòlíì obìnrin kan tó ń jẹ́ Míríámù láti ṣáájú àwọn obìnrin Ísírẹ́lì nínú orin ìṣẹ́gun tí wọ́n kọ ní Òkun Pupa. Ohun tá a kọ́ lára Míríámù ni pé ká nígboyà, ká nígbàgbọ́, ká sì jẹ́ onírẹ̀lẹ̀.

Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ìgbàgbọ́ Wọn​—⁠Àwọn Ọkùnrin àti Obìnrin Tí Bíbélì Sọ̀rọ̀ Nípa Wọn

Ìtẹ̀jáde

Ìgbàgbọ́ Òdodo Ló Máa Mú Kó O Ní Ayọ̀

Ìwé pẹlẹbẹ yìí ṣàlàyé bí àwọn èèyàn láti onírúurú ilẹ̀ ṣe lè láyọ̀ tí wọ́n bá lè mú kí ìgbàgbọ́ wọn jinlẹ̀.