Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Bíbélì orí íńtánẹ́ẹ̀tì

Ka Bíbélì lórí Íńtánẹ́ẹ̀tì tàbí kó o gbọ́ èyí tá a ti kà. O tún lè wa ohùn tá a gbà sílẹ̀ jáde tàbí Bíbélì èdè àwọn adití tó jẹ́ fídíò. Bíbélì Mímọ́ tí Ìtumọ̀ Ayé Tuntun péye, ó sì rọrùn láti kà. A ti tẹ odindi rẹ̀ tàbí apá kan rẹ̀ jáde ní èdè tó lé ní igba ó lé mẹ́wàá [210]. A sì ti tẹ iye tó ju igba ó lé ogójì [240] mílíọ̀nù.

WÒ Ó

BÍBÉLÌ MÍMỌ́ TI ÌTUMỌ̀ AYÉ TUNTUN