Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Lẹ́tà sí Àwọn Hébérù

Orí

1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 11 12 13

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

  • 1

    • Ọlọ́run ń sọ̀rọ̀ nípasẹ̀ Ọmọ rẹ̀ (1-4)

    • Ọmọ ju àwọn áńgẹ́lì lọ (5-14)

  • 2

    • Ká túbọ̀ máa fiyè sí àwọn ohun tí a gbọ́ (1-4)

    • A fi ohun gbogbo sábẹ́ Jésù (5-9)

    • Jésù àti àwọn arákùnrin rẹ̀ (10-18)

      • Olórí Aṣojú ìgbàlà wọn (10)

      • Àlùfáà àgbà tó jẹ́ aláàánú (17)

  • 3

    • Jésù ju Mósè lọ (1-6)

      • Ọlọ́run ló kọ́ ohun gbogbo (4)

    • Ìkìlọ̀ nípa àìnígbàgbọ́ (7-19)

      • “Lónìí, tí ẹ bá fetí sí ohùn rẹ̀” (7, 15)

  • 4

    • Ohun tí kò jẹ́ kí wọ́n wọnú ìsinmi Ọlọ́run (1-10)

    • Ká sapá ká lè wọnú ìsinmi Ọlọ́run (11-13)

      • Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run wà láàyè (12)

    • Jésù, àlùfáà àgbà tó tóbi (14-16)

  • 5

    • Jésù tóbi ju àwọn èèyàn tó jẹ́ àlùfáà àgbà lọ (1-10)

      • Ní ọ̀nà ti Melikisédékì (6, 10)

      • Ó kọ́ ìgbọràn látinú ìyà tó jẹ (8)

      • A máa ní ìgbàlà àìnípẹ̀kun nípasẹ̀ rẹ̀ (9)

    • Ìkìlọ̀ nípa àìdàgbà nípa tẹ̀mí (11-14)

  • 6

    • Ká tẹ̀ síwájú, ká sì dàgbà nípa tẹ̀mí (1-3)

    • Àwọn tó yẹsẹ̀ tún kan Ọmọ mọ́gi (4-8)

    • Ẹ jẹ́ kí ìrètí yín dá yín lójú (9-12)

    • Ìlérí Ọlọ́run dájú (13-20)

      • Ìlérí Ọlọ́run àti ohun tó búra ò lè yí pa dà (17, 18)

  • 7

    • Melikisédékì, ọba àti àlùfáà tó ṣàrà ọ̀tọ̀ (1-10)

    • Bí Jésù ṣe jẹ́ àlùfáà tó tóbi jù (11-28)

      • Kristi lè gbani là pátápátá (25)

  • 8

    • Àgọ́ ìjọsìn tó jẹ mọ́ nǹkan ti ọ̀run (1-6)

    • Ìyàtọ̀ tó wà láàárín májẹ̀mú ti tẹ́lẹ̀ àti májẹ̀mú tuntun (7-13)

  • 9

    • Ìjọsìn mímọ́ ní ibi mímọ́ tó wà láyé (1-10)

    • Kristi wọ ọ̀run pẹ̀lú ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ (11-28)

      • Alárinà májẹ̀mú tuntun (15)

  • 10

    • Fífi ẹran rúbọ ò gbéṣẹ́ (1-4)

      • Òfin jẹ́ òjìji (1)

    • Kristi rúbọ lẹ́ẹ̀kan ṣoṣo láìtún ní ṣe é mọ́ láé (5-18)

    • Ọ̀nà àbáwọlé tuntun tó jẹ́ ọ̀nà ìyè (19-25)

      • Ká má ṣe máa kọ ìpàdé wa sílẹ̀ (24, 25)

    • Ìkìlọ̀ nípa ẹ̀ṣẹ̀ tí a mọ̀ọ́mọ̀ dá (26-31)

    • Ìgboyà àti ìgbàgbọ́ máa jẹ́ ká lè fara dà á (32-39)

  • 11

    • Ohun tí ìgbàgbọ́ túmọ̀ sí (1, 2)

    • Àwọn àpẹẹrẹ ìgbàgbọ́ (3-40)

      • Kò ṣeé ṣe láti ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run dáadáa láìsí ìgbàgbọ́ (6)

  • 12

    • Jésù ni Aláṣepé ìgbàgbọ́ wa (1-3)

      • Àwọsánmà àwọn ẹlẹ́rìí (1)

    • Má fojú kéré ìbáwí látọ̀dọ̀ Jèhófà (4-11)

    • Ẹ ṣe ọ̀nà tó tọ́ fún ẹsẹ̀ yín (12-17)

    • Wọ́n sún mọ́ Jerúsálẹ́mù ti ọ̀run (18-29)

  • 13

    • Ọ̀rọ̀ ìyànjú àti ìkíni tó fi parí ọ̀rọ̀ rẹ̀ (1-25)

      • Ẹ má gbàgbé láti máa ṣe aájò àlejò (2)

      • Kí ìgbéyàwó ní ọlá (4)

      • Ẹ máa ṣègbọràn sí àwọn tó ń mú ipò iwájú (7, 17)

      • Ẹ máa rú ẹbọ ìyìn (15, 16)