Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

B15

Kàlẹ́ńdà Àwọn Hébérù

NÍSÀN (ÁBÍBÙ) March—April

14 Ìrékọjá

15-21 Búrẹ́dì Aláìwú

16 Fífi àwọn àkọ́so ṣe ọrẹ

Òjò àti yìnyín tó yọ́ mú kí odò Jọ́dánì kún sí i

Ọkà Báálì

ÍÍYÀ (SÍFÌ) April—May

14 Ìrékọjá lẹ́yìn àkókò rẹ̀

Ìgbà ẹ̀ẹ̀rùn bẹ̀rẹ̀, kì í sí kùrukùru

Àlìkámà

SÍFÁNÌ May—June

6 Àjọyọ̀ Àwọn Ọ̀sẹ̀ (Pẹ́ńtíkọ́sì)

Ooru ìgbà ẹ̀ẹ̀rùn, ojú ọjọ́ mọ́ kedere

Àlìkámà, àkọ́pọ́n èso ọ̀pọ̀tọ́

TÁMÚSÌ June—July

 

Ooru pọ̀ sí i, ìrì púpọ̀ máa ń sẹ̀ ní agbègbè yìí

Àkọ́pọ́n èso àjàrà

ÁBÌ July—August

 

Ìgbà tí ooru mú jù lọ

Àwọn èso ìgbà ẹ̀ẹ̀rùn

ÉLÚLÌ August—September

 

Ooru ṣì wà

Èso déètì, ọ̀pọ̀tọ́ àti àjàrà

TÍṢÍRÌ (ÉTÁNÍMÙ) September—October

1 Fífun kàkàkí

10 Ọjọ́ Ètùtù

15-21 Àjọyọ̀ Àtíbàbà

22 Àpéjọ ọlọ́wọ̀

Ìgbà ẹ̀ẹ̀rùn parí, òjò àkọ́rọ̀ bẹ̀rẹ̀

Títúlẹ̀

HÉṢÍFÁNÙ (BÚLÌ) October—November

 

Òjò winniwinni

Èso ólífì

KÍSÍLÉFÌ November—December

25 Àjọyọ̀ Ìyàsímímọ́

Òjò ń pọ̀ sí i, ìrì dídì, yìnyín bo òkè

Agbo ẹran kò sí níta mọ́

TÉBÉTÌ December—January

 

Ìgbà tí òtútù mú jù lọ, ìgbà òjò, yìnyín bo òkè

Ohun ọ̀gbìn ń hù

ṢÉBÁTÌ January—February

 

Òtútù ò fi bẹ́ẹ̀ mú mọ́, òjò ṣì ń rọ̀

Álímọ́ńdì yọ ìtànná

ÁDÁRÌ February—March

14, 15 Púrímù

Ààrá ń sán lemọ́lemọ́, yìnyín sì ń já bọ́

Ọ̀gbọ̀

FÍÁDÀ March

Ìgbà méje ni wọ́n máa ń ní oṣù kẹtàlá láàárín ọdún 19