Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÌBÉÈRÈ 9

Kí Nìdí Táwọn Èèyàn Fi Ń Jìyà?

“Ìgbà gbogbo kọ́ ni ẹni tí ẹsẹ̀ rẹ̀ yá máa ń mókè nínú eré ìje, bẹ́ẹ̀ ni kì í ṣe gbogbo ìgbà ni àwọn alágbára máa ń borí lójú ogun, bẹ́ẹ̀ ni àwọn ọlọ́gbọ́n kì í fìgbà gbogbo rí oúnjẹ jẹ, ìgbà gbogbo kọ́ sì ni àwọn olórí pípé máa ń ní ọrọ̀, bákan náà àwọn tó ní ìmọ̀ kì í fìgbà gbogbo ṣe àṣeyọrí, nítorí ìgbà àti èèṣì ń ṣẹlẹ̀ sí gbogbo wọn.”

Oníwàásù 9:11

“Ẹ̀ṣẹ̀ . . . tipasẹ̀ ẹnì kan wọ ayé, . . . ikú sì wá nípasẹ̀ ẹ̀ṣẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni ikú ṣe tàn dé ọ̀dọ̀ gbogbo èèyàn torí pé gbogbo wọn ti dẹ́ṣẹ̀—.”

Róòmù 5:12

“Ìdí tí a ṣe fi Ọmọ Ọlọ́run hàn kedere nìyí, kó lè fọ́ àwọn iṣẹ́ Èṣù túútúú.”

1 Jòhánù 3:8

“Gbogbo ayé wà lábẹ́ agbára ẹni burúkú náà.”

1 Jòhánù 5:19