Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

B12-B

Ọ̀sẹ̀ Tí Jésù Lò Kẹ́yìn Kó Tó Kú (Apá Kejì)

Jerúsálẹ́mù àti Agbègbè Rẹ̀

  1. Tẹ́ńpìlì

  2.   Ọgbà Gẹ́tísémánì (?)

  3.    Ààfin Gómìnà

  4.   Ilé Káyáfà (?)

  5.   Ààfin Tí Hẹ́rọ́dù Áńtípà Lò (?)

  6. Adágún Omi Bẹtisátà

  7. Adágún Omi Sílóámù

  8.   Gbọ̀ngàn Sàhẹ́ndìrìn (?)

  9.   Gọ́gọ́tà (?)

  10. Ákélídámà (?)

     Lọ sí ọjọ́ tó o fẹ́:  Nísàn 12 |  Nísàn 13 |  Nísàn 14 |  Nísàn 15 |  Nísàn 16

 Nísàn 12

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀ (Ọjọ́ àwọn Júù máa ń bẹ̀rẹ̀ nígbà tí oòrùn bá wọ̀, ó sì máa ń parí sí ìgbà tí oòrùn bá wọ̀)

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ

  • Òun àtàwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ jọ wà níbi tó pa rọ́rọ́

  • Júdásì ṣètò bí wọ́n ṣe máa mú Jésù

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀

 Nísàn 13

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ

  • Pétérù àti Jòhánù múra sílẹ̀ fún Ìrékọjá

  • Jésù àtàwọn àpọ́sítélì yòókù dé ní ọjọ́rọ̀

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀

 Nísàn 14

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀

  • Òun àtàwọn àpọ́sítélì rẹ̀ jẹ Ìrékọjá

  • Ó fọ ẹsẹ̀ àwọn àpọ́sítélì

  • Ó ní kí Júdásì máa lọ

  • Ó dá Oúnjẹ Alẹ́ Olúwa sílẹ̀

  • Júdásì fi í hàn, wọ́n sì mú un ní ọgbà Gẹ́tísémánì ( 2)

  • Àwọn àpọ́sítélì sá

  • Ó jẹ́jọ́ níwájú Sàhẹ́ndìrìn nílé Káyáfà ( 4)

  • Pétérù sẹ́ Jésù

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ

  • Ó tún jẹ́jọ́ níwájú Sàhẹ́ndìrìn ( 8)

  • Wọ́n mú un lọ sọ́dọ̀ Pílátù ( 3), lẹ́yìn náà sọ́dọ̀ Hẹ́rọ́dù ( 5), wọ́n tún dá a pa dà sọ́dọ̀ Pílátù ( 3)

  • Wọ́n dájọ́ ikú fún un, wọ́n sì pa á ní Gọ́gọ́tà ( 9)

  • Ó kú ní nǹkan bí aago mẹ́ta ọ̀sán

  • Wọ́n gbé òkú rẹ̀ lọ sin

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀

 Nísàn 15 (Sábáàtì)

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ

  • Pílátù gbà pé kí wọ́n fi àwọn ẹ̀ṣọ́ ṣọ́ sàréè Jésù

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀

 Nísàn 16

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀

  • Wọ́n ra èròjà tó ń ta sánsán púpọ̀ sí i láti sin òkú rẹ̀

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN YỌ

  • Ó jíǹde

  • Ó fara han àwọn ọmọ ẹ̀yìn

ÌGBÀ TÍ OÒRÙN WỌ̀