Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

B14-A

Òwò àti Ọrọ̀ Ajé

  • Òṣùwọ̀n Nǹkan Olómi

  • Kọ́ọ̀ (Báàtì 10 / Hínì 60)

    Lítà 220 / Gálọ́ọ̀nù 58.1

  • Báàtì (Hínì 6)

    Lítà 22 / Gálọ́ọ̀nù 5.81

  • Hínì (Lọ́ọ̀gì 12)

    Lítà 3.67 / Páìntì 7.75

  • Lọ́ọ̀gì (Hínì 1 ⁄ 12)

    Lítà 0.31 / Páìntì 0.66

  • Òṣùwọ̀n Nǹkan Gbígbẹ

  • Hómérì (Kọ́ọ̀ 1 / Eéfà 10)

    Lítà 220 /Kúọ̀tì 200

  • Eéfà (Síà 3 / Ómérì 10)

    Lítà 22 /Kúọ̀tì 20

  • Síà (Ómérì 31 ⁄ 3)

    Lítà 7.33 / Kúọ̀tì 6.66

  • Ómérì (Káàbù 14 ⁄ 5)

    Lítà 2.2 / Kúọ̀tì 2

  • Káàbù

    Lítà 1.22 / Kúọ̀tì 1.11

  • Kúọ̀tì

    Lítà 1.08 / Kúọ̀tì 0.98

  • Ìdíwọ̀n Nǹkan Gbọọrọ

  • Ọ̀pá esùsú gígùn (Ìgbọ̀nwọ́ gígùn 6)

    Mítà 3.11 / Ẹsẹ̀ bàtà 10.2

  • Esùsú (Ìgbọ̀nwọ́ 6)

    Mítà 2.67 / Ẹsẹ̀ bàtà 8.75

  • Fátọ́ọ̀mù

    Mítà 1.8 / Ẹsẹ̀ bàtà 6

  • Ìgbọ̀nwọ́ gígùn (Ìbú ọwọ́ 7)

    Sẹ̀ǹtímítà 51.8 / Ínǹṣì 20.4

  • Ìgbọ̀nwọ́ (Ìbú àtẹ́lẹwọ́ 2 / Ìbú ọwọ́ 6)

    Sẹ̀ǹtímítà 44.5 / Ínǹṣì 17.5

  • Ìgbọ̀nwọ́ kékeré

    Sẹ̀ǹtímítà 38 / Ínǹṣì 15

  • Sítédíọ̀mù Róòmù 1

    Máìlì Róòmù 1 ⁄ 8= Mítà 185 / Ẹsẹ̀ bàtà 606.95

  1. 1 Ìbú ìka (Ìbú ọwọ́ 1 ⁄ 4)

    Sẹ̀ǹtímítà 1.85 / Ínǹṣì 0.73

  2. 2 Ìbú ọwọ́ (Ìbú ìka 4)

    Sẹ̀ǹtímítà 7.4 / Ínǹṣì 2.9

  3. 3 Ìbú àtẹ́lẹwọ́ (Ìbú ọwọ́ 3)

    Sẹ̀ǹtímítà 22.2 / Ínǹṣì 8.75