Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Lẹ́tà Kìíní sí Àwọn Ará Kọ́ríńtì

Orí

1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 11 12 13 14 15 16

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

  • 1

    • Ìkíni (1-3)

    • Pọ́ọ̀lù dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run nítorí àwọn ará Kọ́ríńtì (4-9)

    • Ó gbà wọ́n níyànjú pé kí wọ́n wà níṣọ̀kan (10-17)

    • Kristi, agbára àti ọgbọ́n Ọlọ́run (18-25)

    • Ẹ máa yangàn nínú Jèhófà nìkan (26-31)

  • 2

    • Iṣẹ́ ìwàásù Pọ́ọ̀lù ní Kọ́ríńtì (1-5)

    • Ọgbọ́n Ọlọ́run ju ti èèyàn lọ (6-10)

    • Ẹni tara àti ẹni tẹ̀mí (11-16)

  • 3

    • Àwọn ará Kọ́ríńtì ṣì jẹ́ ẹni tara (1-4)

    • Ọlọ́run ń mú kó dàgbà (5-9)

      • Alábàáṣiṣẹ́ pẹ̀lú Ọlọ́run (9)

    • Fi ohun tí kò lè jóná kọ́lé (10-15)

    • Ẹ̀yin ni tẹ́ńpìlì Ọlọ́run (16, 17)

    • Ọgbọ́n ayé jẹ́ òmùgọ̀ lọ́dọ̀ Ọlọ́run (18-23)

  • 4

    • Ó yẹ kí ìríjú jẹ́ olóòótọ́ (1-5)

    • Ẹ̀mí ìrẹ̀lẹ̀ àwọn òjíṣẹ́ tó jẹ́ Kristẹni (6-13)

      • ‘Má ṣe kọjá ohun tó wà lákọsílẹ̀’ (6)

      • Àwọn Kristẹni jẹ́ ìran àpéwò (9)

    • Pọ́ọ̀lù ń bójú tó àwọn tó jẹ́ ọmọ rẹ̀ nípa tẹ̀mí (14-21)

  • 5

    • Ẹjọ́ ìṣekúṣe tó wáyé (1-5)

    • Ìwúkàrà díẹ̀ ló ń mú gbogbo ìṣùpọ̀ wú (6-8)

    • Ẹ mú ẹni burúkú náà kúrò (9-13)

  • 6

    • Àwọn ará ń gbéra wọn lọ sílé ẹjọ́ (1-8)

    • Àwọn tí kò ní jogún Ìjọba Ọlọ́run (9-11)

    • Ẹ máa yin Ọlọ́run lógo nínú ara yín (12-20)

      • “Ẹ máa sá fún ìṣekúṣe!” (18)

  • 7

    • Ìmọ̀ràn fún àwọn tí kò gbéyàwó àti àwọn tó ti gbéyàwó (1-16)

    • Ẹ wà ní ipò tí ẹ wà nígbà tí a pè yín (17-24)

    • Àwọn tí kò gbéyàwó àti àwọn opó (25-40)

      • Àǹfààní tó wà nínú kéèyàn wà láìgbéyàwó (32-35)

      • Gbéyàwó “kìkì nínú Olúwa” (39)

  • 8

    • Ọ̀rọ̀ nípa oúnjẹ tí wọ́n fi rúbọ sí òrìṣà (1-13)

      • Ní tiwa, Ọlọ́run kan ṣoṣo ló wà (5, 6)

  • 9

    • Àpẹẹrẹ Pọ́ọ̀lù nínú iṣẹ́ àpọ́sítélì (1-27)

      • “O ò gbọ́dọ̀ di ẹnu akọ màlúù” (9)

      • ‘Mo gbé tí mi ò bá wàásù!’ (16)

      • Mo di ohun gbogbo fún gbogbo èèyàn (19-23)

      • Bí a ṣe lè kíyè sára nínú eré ìje ìyè (24-27)

  • 10

    • Àpẹẹrẹ ìkìlọ̀ látinú ìtàn àwọn ọmọ Ísírẹ́lì (1-13)

    • Àpẹẹrẹ ìkìlọ̀ nípa ìbọ̀rìṣà (14-22)

      • Tábìlì Jèhófà àti tábìlì àwọn ẹ̀mí èṣù (21)

    • Òmìnira àti gbígba tàwọn ẹlòmíì rò (23-33)

      • “Ẹ máa ṣe ohun gbogbo fún ògo Ọlọ́run” (31)

  • 11

    • “Ẹ máa fara wé mi” (1)

    • Ipò orí àti bíbo orí (2-16)

    • Ṣíṣe Oúnjẹ Alẹ́ Olúwa (17-34)

  • 12

    • Ẹ̀bùn ti ẹ̀mí (1-11)

    • Ara kan, ẹ̀yà ara púpọ̀ (12-31)

  • 13

    • Ìfẹ́ jẹ́ ọ̀nà tó ta yọ (1-13)

  • 14

    • Àwọn ẹ̀bùn ìsọtẹ́lẹ̀ àti èdè àjèjì (1-25)

    • Àwọn ìjọ Kristẹni tó wà létòlétò (26-40)

      • Àyè àwọn obìnrin nínú ìjọ (34, 35)

  • 15

    • Àjíǹde Kristi (1-11)

    • Àjíǹde jẹ́ ìpìlẹ̀ ìgbàgbọ́ (12-19)

    • Àjíǹde Kristi jẹ́ àmì ìdánilójú (20-34)

    • Ara ìyára àti ara tẹ̀mí (35-49)

    • Àìkú àti àìdíbàjẹ́ (50-57)

    • Ẹ ní ohun púpọ̀ láti ṣe nínú iṣẹ́ Olúwa (58)

  • 16

    • Wọ́n kó nǹkan jọ fún àwọn Kristẹni tó wà ní Jerúsálẹ́mù (1-4)

    • Ètò ìrìn àjò Pọ́ọ̀lù (5-9)

    • Ó ṣètò bí Tímótì àti Àpólò ṣe máa bẹ àwọn ará wò (10-12)

    • Ọ̀rọ̀ ìyànjú àti ìkíni (13-24)