Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Lẹ́tà sí Àwọn Ará Kólósè

Orí

1 2 3 4

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

  • 1

    • Ìkíni (1, 2)

    • Pọ́ọ̀lù dúpẹ́ nítorí ìgbàgbọ́ àwọn ará Kólósè (3-8)

    • Àdúrà pé kí wọ́n máa dàgbà sí i nípa tẹ̀mí (9-12)

    • Ipa àrà ọ̀tọ̀ tí Kristi kó (13-23)

    • Iṣẹ́ àṣekára tí Pọ́ọ̀lù ṣe fún ìjọ (24-29)

  • 2

    • Kristi, àṣírí mímọ́ Ọlọ́run (1-5)

    • Ẹ máa ṣọ́ra fún àwọn ẹlẹ́tàn (6-15)

    • Ohun gidi náà ni Kristi (16-23)

  • 3

    • Ìwà tuntun àti ìwà àtijọ́ (1-17)

      • Ẹ sọ àwọn ẹ̀yà ara yín di òkú (5)

      • Ìfẹ́ jẹ́ ìdè ìrẹ́pọ̀ pípé (14)

    • Ìmọ̀ràn fún ìdílé Kristẹni (18-25)

  • 4

    • Ìmọ̀ràn fún àwọn ọ̀gá (1)

    • “Ẹ tẹra mọ́ àdúrà gbígbà” (2-4)

    • Ẹ máa fi ọgbọ́n bá àwọn tó wà lóde lò (5, 6)

    • Ìkíni tó fi parí ọ̀rọ̀ rẹ̀ (7-18)