Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Lẹ́tà Jémíìsì

Orí

1 2 3 4 5

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

  • 1

    • Ìkíni (1)

    • Ìfaradà ń jẹ́ ká láyọ̀ (2-15)

      • A máa ń dán ìgbàgbọ́ wò ní ti bó ṣe jẹ́ ojúlówó tó (3)

      • Ẹ máa fi ìgbàgbọ́ béèrè (5-8)

      • Ìfẹ́ ọkàn máa ń yọrí sí ẹ̀ṣẹ̀ àti ikú (14, 15)

    • Gbogbo ẹ̀bùn rere wá láti òkè (16-18)

    • Olùgbọ́ àti olùṣe ọ̀rọ̀ náà (19-25)

      • Ẹni tó ń wo ara rẹ̀ nínú dígí (23, 24)

    • Ìjọsìn tó mọ́, tí kò sì ní ẹ̀gbin (26, 27)

  • 2

    • Ojúsàájú jẹ́ ẹ̀ṣẹ̀ (1-13)

      • Ìfẹ́ ni ọba òfin (8)

    • Ìgbàgbọ́ láìsí àwọn iṣẹ́ jẹ́ òkú (14-26)

      • Àwọn ẹ̀mí èṣù gbà, jìnnìjìnnì sì bò wọ́n (19)

      • A pe Ábúráhámù ní ọ̀rẹ́ Jèhófà (23)

  • 3

    • Bí a ṣe lè kápá ahọ́n (1-12)

      • Kí ọ̀pọ̀ má ṣe di olùkọ́ (1)

    • Ọgbọ́n tó wá láti òkè (13-18)

  • 4

    • Ẹ má ṣe jẹ́ ọ̀rẹ́ ayé (1-12)

      • Ẹ dojú ìjà kọ Èṣù (7)

      • Ẹ sún mọ́ Ọlọ́run (8)

    • Ìkìlọ̀ pé ká má ṣe gbéra ga (13-17)

      • “Tí Jèhófà bá fẹ́” (15)

  • 5

    • Ìkìlọ̀ fún àwọn ọlọ́rọ̀ (1-6)

    • Ọlọ́run ń bù kún àwọn tó ní sùúrù àti ìfaradà (7-11)

    • Ẹ jẹ́ kí “bẹ́ẹ̀ ni” yín jẹ́ bẹ́ẹ̀ ni (12)

    • Àdúrà ìgbàgbọ́ lágbára (13-18)

    • Ran ẹlẹ́ṣẹ̀ lọ́wọ́ kó lè yí pa dà (19, 20)