Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Lẹ́tà Kejì sí Tímótì

Orí

1 2 3 4

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

  • 1

    • Ìkíni (1, 2)

    • Pọ́ọ̀lù dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run torí ìgbàgbọ́ Tímótì (3-5)

    • Jẹ́ kí ẹ̀bùn Ọlọ́run máa jó bí iná (6-11)

    • Máa tẹ̀ lé àwọn ọ̀rọ̀ tó ṣàǹfààní (12-14)

    • Àwọn ọ̀tá Pọ́ọ̀lù àtàwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ (15-18)

  • 2

    • Fi ọ̀rọ̀ náà síkàáwọ́ àwọn ọkùnrin tó kúnjú ìwọ̀n (1-7)

    • Jìyà nítorí ìhìn rere (8-13)

    • Máa lo ọ̀rọ̀ Ọlọ́run bó ṣe yẹ (14-19)

    • Sá fún àwọn ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ìgbà ọ̀dọ́ (20-22)

    • Ohun tí o lè ṣe sí àwọn alátakò (23-26)

  • 3

    • Nǹkan máa le gan-an ní àwọn ọjọ́ ìkẹyìn (1-7)

    • Tẹ̀ lé àpẹẹrẹ Pọ́ọ̀lù pẹ́kípẹ́kí (8-13)

    • “Má ṣe fi àwọn nǹkan tí o ti kọ́ sílẹ̀” (14-17)

      • Gbogbo Ìwé Mímọ́ ni Ọlọ́run mí sí (16)

  • 4

    • “Ṣe iṣẹ́ òjíṣẹ́ rẹ láìkù síbì kan” (1-5)

      • Wàásù ọ̀rọ̀ náà láìfi falẹ̀ (2)

    • “Mo ti ja ìjà rere náà” (6-8)

    • Àwọn ọ̀rọ̀ ara ẹni (9-18)

    • Ìkíni tó fi parí ọ̀rọ̀ rẹ̀ (19-22)