Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ìwé Rúùtù

Orí

1 2 3 4

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

  • 1

    • Élímélékì àti ìdílé rẹ̀ kó lọ sí Móábù (1, 2)

    • Náómì, Ọ́pà àti Rúùtù di opó (3-6)

    • Rúùtù kò fi Náómì àti Jèhófà sílẹ̀ (7-17)

    • Náómì pa dà sí Bẹ́tílẹ́hẹ́mù, Rúùtù tẹ̀ lé e (18-22)

  • 2

    • Rúùtù pèéṣẹ́ ní oko Bóásì (1-3)

    • Rúùtù àti Bóásì pàdé (4-16)

    • Rúùtù sọ fún Náómì bí Bóásì ṣe ṣojúure sí òun (17-23)

  • 3

    • Náómì sọ ohun tí Rúùtù máa ṣe (1-4)

    • Rúùtù àti Bóásì ní ibi ìpakà (5-15)

    • Rúùtù pa dà sọ́dọ̀ Náómì (16-18)

  • 4

    • Bóásì tún ìdílé Élímélékì rà (1-12)

    • Rúùtù bí Óbédì fún Bóásì (13-17)

    • Ìran Dáfídì (18-22)