Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ìwé Orin Sólómọ́nì

Orí

1 2 3 4 5 6 7 8

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

  • Ọ̀DỌ́BÌNRINÚLÁMÁÍTÌ WÀ NÍNÚ ÀGỌ́BA SÓLÓMỌ́NÌ (1:1–3:5)

    • 1

      • Orin tó ju orin lọ (1)

      • Ọ̀dọ́bìnrin (2-7)

      • Àwọn ọmọbìnrin Jerúsálẹ́mù (8)

      • Ọba (9-11)

        • “A máa fi wúrà ṣe ohun ọ̀ṣọ́ fún ọ” (11)

      • Ọ̀dọ́bìnrin (12-14)

        • “Olólùfẹ́ mi dà bí àpò òjíá tó ń ta sánsán” (13)

      • Olùṣọ́ àgùntàn (15)

        • “O rẹwà gan-an, olólùfẹ́ mi”

      • Ọ̀dọ́bìnrin(16, 17)

        • “O rẹwà púpọ̀, olólùfẹ́ mi” (16)

    • 2

      • Ọ̀dọ́bìnrin (1)

        • “Mo dà bí òdòdó sáfúrónì”

      • Olùṣọ́ àgùntàn (2)

        • ‘Olólùfẹ́ mi dà bí òdòdó lílì’

      • Ọ̀dọ́bìnrin (3-14)

        • ‘Ẹ má ṣe ru ìfẹ́ sókè títí á fi wá fúnra rẹ̀’ (7)

        • Ohun tí olùṣọ́ àgùntàn sọ (10b-14)

          • “Arẹwà mi, tẹ̀ lé mi ká lọ” (10b, 13)

      • Àwọn arákùnrin ọ̀dọ́bìnrin náà (15)

        • “Bá wa mú àwọn kọ̀lọ̀kọ̀lọ̀”

      • Ọ̀dọ́bìnrin (16, 17)

        • “Èmi ni mo ni olólùfẹ́ mi, òun ló sì ni mí” (16)

    • 3

      • Ọ̀dọ́bìnrin (1-5)

        • ‘Ní òru, mo wá ẹni tí mo nífẹ̀ẹ́’ (1)

  • Ọ̀DỌ́BÌNRINÚLÁMÁÍTÌ WÀ NÍ JERÚSÁLẸ́MÙ (3:6–8:4)

    • 3

      • Àwọn ọmọbìnrin Síónì (6-11)

        • Sólómọ́nì àti àwọn tó ń tẹ̀ lé e

    • 4

      • Olùṣọ́ àgùntàn (1-5)

        • “O rẹwà gan-an, olólùfẹ́ mi” (1)

      • Ọ̀dọ́bìnrin (6)

      • Olùṣọ́ àgùntàn (7-16a)

        • ‘O ti gbà mí lọ́kàn, ìyàwó mi’ (9)

      • Ọ̀dọ́bìnrin (16b)

    • 5

      • Olùṣọ́ àgùntàn (1a)

      • Àwọn obìnrin Jerúsálẹ́mù (1b)

        • ‘Ẹ mu ìfẹ́ yó!’

      • Ọ̀dọ́bìnrin (2-8)

        • Ó sọ àlá rẹ̀

      • Àwọn ọmọbìnrin Jerúsálẹ́mù (9)

        • ‘Kí ló mú kí olólùfẹ́ rẹ dára ju àwọn míì lọ?’

      • Ọ̀dọ́bìnrin (10-16)

        • “Kò sí ẹni tí a lè fi í wé láàárín ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá ọkùnrin” (10)

    • 6

      • Àwọn ọmọbìnrin Jerúsálẹ́mù (1)

      • Ọ̀dọ́bìnrin (2, 3)

        • “Olólùfẹ́ mi ló ni mí, èmi ni mo sì ni olólùfẹ́ mi” (3)

      • Ọba (4-10)

        • “O rẹwà bíi Tírísà” (4)

        • Ohun tí àwọn obìnrin sọ (10)

      • Ọ̀dọ́bìnrin (11, 12)

      • Ọba (àti àwọn míì) (13a)

      • Ọ̀dọ́bìnrin (13b)

      • Ọba (àti àwọn míì) (13d)

    • 7

      • Ọba (1-9a)

        • “O mà wuni o, ìwọ obìnrin tí mo nífẹ̀ẹ́” (6)

      • Ọ̀dọ́bìnrin (9b-13)

        • “Olólùfẹ́ mi ló ni mí, èmi sì ni ọkàn rẹ̀ ń fà sí” (10)

    • 8

      • Ọ̀dọ́bìnrin (1-4)

        • “Ká ní o dà bí arákùnrin mi ni” (1)

  • Ọ̀DỌ́BÌNRINÚLÁMÁÍTÌ PA DÀ, Ó JẸ́ ADÚRÓTINI (8:5-14)

    • 8

      • Àwọn arákùnrin ọ̀dọ́bìnrin náà (5a)

        • ‘Ta nìyí, tó fara ti olólùfẹ́ rẹ̀?’

      • Ọ̀dọ́bìnrin (5b-7)

        • “Ìfẹ́ lágbára bí ikú” (6)

      • Àwọn arákùnrin ọ̀dọ́bìnrin náà (8, 9)

        • “Tó bá jẹ́ ògiri, . . . àmọ́ tó bá jẹ́ ilẹ̀kùn, . . .” (9)

      • Ọ̀dọ́bìnrin (10-12)

        • “Ògiri ni mí” (10)

      • Olùṣọ́ àgùntàn (13)

        • ‘Jẹ́ kí n gbọ́ ohùn rẹ’

      • Ọ̀dọ́bìnrin (14)

        • “Yára bí egbin”