Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ìwé Míkà

Orí

1 2 3 4 5 6 7

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

  • 1

    • Ohun tó máa ṣẹlẹ̀ sí Samáríà àti Júdà (1-16)

      • Ẹ̀ṣẹ̀ àti ọ̀tẹ̀ ló fa wàhálà náà (5)

  • 2

    • Àwọn tó ń ni ẹlòmíì lára gbé! (1-11)

    • Ọlọ́run tún mú kí Ísírẹ́lì wà ní ìṣọ̀kan (12, 13)

      • Ariwo àwọn èèyàn yóò gba ilẹ̀ náà kan (12)

  • 3

    • Ọlọ́run bá àwọn olórí àti àwọn wòlíì wí (1-12)

      • Ẹ̀mí Jèhófà fún Míkà ní agbára (8)

      • Àwọn àlùfáà ń gba owó kí wọ́n tó kọ́ni (11)

      • Jerúsálẹ́mù yóò di àwókù ilé (12)

  • 4

    • Òkè Jèhófà yóò ga ju àwọn yòókù lọ (1-5)

      • Wọ́n á fi idà rọ ohun ìtúlẹ̀ (3)

      • “Àwa yóò máa rìn ní orúkọ Jèhófà” (5)

    • Ọlọ́run yóò mú kí Síónì pa dà di alágbára (6-13)

  • 5

    • Alákòóso kan yóò lágbára ní gbogbo ayé (1-6)

      • Alákòóso náà yóò wá láti Bẹ́tílẹ́hẹ́mù (2)

    • Àwọn tó ṣẹ́ kù yóò dà bí ìrì àti bíi kìnnìún (7-9)

    • Ọlọ́run máa fọ ilẹ̀ náà mọ́ (10-15)

  • 6

    • Ọlọ́run pe Ísírẹ́lì lẹ́jọ́ (1-5)

    • Kí ni Jèhófà fẹ́? (6-8)

      • Ìdájọ́ òdodo, ìṣòtítọ́, ìrẹ̀lẹ̀ (8)

    • Ẹ̀bi Ísírẹ́lì àti ìyà tí wọ́n máa jẹ (9-16)

  • 7

    • Ìwàkiwà Ísírẹ́lì (1-6)

      • “Ará ilé ẹni ni ọ̀tá ẹni” (6)

    • “Màá dúró de Ọlọ́run” (7)

    • Ọlọ́run dá àwọn èèyàn rẹ̀ láre (8-13)

    • Míkà gbàdúrà, ó sì yin Ọlọ́run (14-20)

      • Jèhófà dáhùn (15-17)

      • ‘Ta ló dà bíi Jèhófà?’ (18)