Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ìwé Hágáì

Orí

1 2

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

  • 1

    • Jèhófà bá wọn wí torí wọn ò tún tẹ́ńpìlì kọ́ (1-11)

      • ‘Ṣé àsìkò yìí ló yẹ kí ẹ máa gbé inú àwọn ilé tí ẹ fi pákó ṣe lọ́ṣọ̀ọ́?’ (4)

      • “Ẹ kíyè sí àwọn ohun tí ẹ̀ ń ṣe” (5)

      • Wọ́n ń fún irúgbìn tó pọ̀, àmọ́ díẹ̀ ni wọ́n ń kórè (6)

    • Àwọn èèyàn náà fetí sí ohùn Jèhófà (12-15)

  • 2

    • Ògo yóò kún inú tẹ́ńpìlì kejì (1-9)

      • Ọlọ́run yóò mi gbogbo orílẹ̀-èdè jìgìjìgì (7)

      • Àwọn ohun iyebíye nínú gbogbo orílẹ̀-èdè yóò wọlé wá (7)

    • Ọlọ́run bù kún wọn torí pé wọ́n tún tẹ́ńpìlì kọ́ (10-19)

      • Ìjẹ́mímọ́ kò lè ràn (10-14)

    • Iṣẹ́ tí Ọlọ́run rán sí Serubábélì (20-23)

      • ‘Èmi yóò ṣe ọ́ bí òrùka èdìdì’ (23)