Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Lẹ́tà Kìíní sí Àwọn Ará Tẹsalóníkà

Orí

1 2 3 4 5

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

  • 1

    • Ìkíni (1)

    • Pọ́ọ̀lù dúpẹ́ nítorí ìgbàgbọ́ àwọn ará Tẹsalóníkà (2-10)

  • 2

    • Iṣẹ́ òjíṣẹ́ Pọ́ọ̀lù ní Tẹsalóníkà (1-12)

    • Àwọn ará Tẹsalóníkà gba ọ̀rọ̀ Ọlọ́run (13-16)

    • Àárò àwọn ará Tẹsalóníkà ń sọ Pọ́ọ̀lù (17-20)

  • 3

    • Ojú Pọ́ọ̀lù wà lọ́nà bó ṣe ń dúró ní Áténì (1-5)

    • Ìròyìn tó ń tuni nínú tí Tímótì mú wá (6-10)

    • Àdúrà fún àwọn ará Tẹsalóníkà (11-13)

  • 4

    • Ìkìlọ̀ lórí ìṣekúṣe (1-8)

    • Ẹ túbọ̀ nífẹ̀ẹ́ ara yín (9-12)

      • “Ẹ má yọjú sí ọ̀rọ̀ ọlọ́rọ̀” (11)

    • Àwọn tó kú nínú Kristi ló máa kọ́kọ́ dìde (13-18)

  • 5

    • Ọjọ́ Jèhófà ń bọ̀ (1-5)

      • “Àlàáfíà àti ààbò!” (3)

    • Ẹ wà lójúfò, ẹ máa ronú bó ṣe tọ́ (6-11)

    • Ọ̀rọ̀ ìyànjú (12-24)

    • Ìkíni tó fi parí ọ̀rọ̀ rẹ̀ (25-28)