Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ìwé Kíróníkà Kìíní

Orí

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

  • 1

    • Látọ̀dọ̀ Ádámù dé ọ̀dọ̀ Ábúráhámù (1-27)

    • Àwọn àtọmọdọ́mọ Ábúráhámù (28-37)

    • Àwọn ọmọ Édómù àti àwọn ọba wọn pẹ̀lú àwọn Séríkí wọn (38-54)

  • 2

    • Àwọn ọmọ 12 tí Ísírẹ́lì bí (1, 2)

    • Àwọn àtọmọdọ́mọ Júdà (3-55)

  • 3

    • Àwọn àtọmọdọ́mọ Dáfídì (1-9)

    • Àwọn ọmọ tó wá láti ìdílé ọba Dáfídì (10-24)

  • 4

    • Àwọn àtọmọdọ́mọ Júdà tó ṣẹ́ kù (1-23)

      • Jábésì àti àdúrà rẹ̀ (9, 10)

    • Àwọn àtọmọdọ́mọ Síméónì (24-43)

  • 5

    • Àwọn àtọmọdọ́mọ Rúbẹ́nì (1-10)

    • Àwọn àtọmọdọ́mọ Gádì (11-17)

    • Wọ́n ṣẹ́gun àwọn ọmọ Hágárì (18-22)

    • Ààbọ̀ ẹ̀yà Mánásè (23-26)

  • 6

    • Àwọn àtọmọdọ́mọ Léfì (1-30)

    • Àwọn akọrin inú tẹ́ńpìlì (31-47)

    • Àwọn àtọmọdọ́mọ Áárónì (48-53)

    • Àwọn ibi tí àwọn ọmọ Léfì gbé (54-81)

  • 7

    • Àwọn àtọmọdọ́mọ Ísákà (1-5), ti Bẹ́ńjámínì (6-12), ti Náfútálì (13), ti Mánásè (14-19), ti Éfúrémù (20-29) àti ti Áṣérì (30-40)

  • 8

    • Àwọn àtọmọdọ́mọ Bẹ́ńjámínì (1-40)

      • Ìlà ìdílé Sọ́ọ̀lù (33-40)

  • 9

    • Àwọn orúkọ tó wà nínú àkọsílẹ̀ ìlà ìdílé lẹ́yìn tí wọ́n dé láti ìgbèkùn (1-34)

    • A tún orúkọ àwọn tó wà nínú ìdílé Sọ́ọ̀lù kọ (35-44)

  • 10

    • Ikú Sọ́ọ̀lù àti àwọn ọmọ rẹ̀ (1-14)

  • 11

    • Gbogbo Ísírẹ́lì fòróró yan Dáfídì ṣe ọba (1-3)

    • Dáfídì gba Síónì (4-9)

    • Àwọn jagunjagun Dáfídì tó lákíkanjú (10-47)

  • 12

    • Àwọn tó ń ti ìjọba Dáfídì lẹ́yìn (1-40)

  • 13

    • Wọ́n gbé Àpótí wá láti Kiriati-jéárímù (1-14)

      • Ọlọ́run pa Úsà (9, 10)

  • 14

    • Ọlọ́run fìdí ìjọba Dáfídì múlẹ̀ (1, 2)

    • Ìdílé Dáfídì (3-7)

    • Wọ́n ṣẹ́gun àwọn Filísínì (8-17)

  • 15

    • Àwọn ọmọ Léfì gbé Àpótí lọ sí Jerúsálẹ́mù (1-29)

      • Míkálì pẹ̀gàn Dáfídì (29)

  • 16

    • Wọ́n gbé Àpótí náà sínú àgọ́ (1-6)

    • Orin ìdúpẹ́ tí Dáfídì kọ (7-36)

      • “Jèhófà ti di Ọba!” (31)

    • Iṣẹ́ ìsìn níwájú Àpótí náà (37-43)

  • 17

    • Dáfídì kò ní kọ́ tẹ́ńpìlì (1-6)

    • Ọlọ́run bá Dáfídì dá májẹ̀mú ìjọba (7-15)

    • Àdúrà ìdúpẹ́ tí Dáfídì gbà (16-27)

  • 18

    • Àwọn tí Dáfídì ṣẹ́gun (1-13)

    • Ìjọba Dáfídì (14-17)

  • 19

    • Àwọn ọmọ Ámónì dójú ti àwọn òjíṣẹ́ Dáfídì (1-5)

    • Wọ́n ṣẹ́gun Ámónì àti Síríà (6-19)

  • 20

    • Wọ́n gba Rábà (1-3)

    • Wọ́n pa àwọn òmìrán Filísínì (4-8)

  • 21

    • Ìkànìyàn tí kò bófin mu tí Dáfídì ṣe (1-6)

    • Ìyà tí Jèhófà fi jẹ wọ́n (7-17)

    • Dáfídì mọ pẹpẹ (18-30)

  • 22

    • Ètò tí Dáfídì ṣe sílẹ̀ fún kíkọ́ tẹ́ńpìlì (1-5)

    • Dáfídì sọ ohun tí Sólómọ́nì máa ṣe fún un (6-16)

    • Ó ní kí àwọn ìjòyè ran Sólómọ́nì lọ́wọ́ (17-19)

  • 23

    • Dáfídì ṣètò àwọn ọmọ Léfì (1-32)

      • A ya Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ sọ́tọ̀ (13)

  • 24

    • Dáfídì ṣètò àwọn àlùfáà sí àwùjọ 24 (1-19)

    • Àwọn iṣẹ́ míì tí a fún àwọn ọmọ Léfì (20-31)

  • 25

    • Àwọn olórin àti àwọn akọrin ilé Ọlọ́run (1-31)

  • 26

    • A pín àwọn aṣọ́bodè sí àwùjọ-àwùjọ (1-19)

    • Àwọn olùtọ́jú ibi ìṣúra àti àwọn òṣìṣẹ́ míì (20-32)

  • 27

    • Àwọn aláṣẹ nídìí iṣẹ́ ọba (1-34)

  • 28

    • Ọ̀rọ̀ tí Dáfídì sọ lórí kíkọ́ tẹ́ńpìlì (1-8)

    • Ó sọ ohun tí Sólómọ́nì máa ṣe; ó fún un ní àwòrán ìkọ́lé (9-21)

  • 29

    • Ọrẹ fún tẹ́ńpìlì (1-9)

    • Àdúrà Dáfídì (10-19)

    • Inú àwọn èèyàn dùn; ìjọba Sólómọ́nì (20-25)

    • Ikú Dáfídì (26-30)