Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ìwé Àwọn Ọba Kìíní

Orí

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

  • 1

    • Dáfídì àti Ábíṣágì (1-4)

    • Ádóníjà wá ọ̀nà láti gorí ìtẹ́ (5-10)

    • Nátánì àti Bátí-ṣébà gbé ìgbésẹ̀ (11-27)

    • Dáfídì pàṣẹ pé kí wọ́n fòróró yan Sólómọ́nì (28-40)

    • Ádóníjà sá lọ sí ibi pẹpẹ (41-53)

  • 2

    • Dáfídì fún Sólómọ́nì ní ìtọ́ni (1-9)

    • Dáfídì kú; Sólómọ́nì gorí ìtẹ́ (10-12)

    • Ọ̀tẹ̀ Ádóníjà yọrí sí ikú fún un (13-25)

    • Ọba lé Ábíátárì kúrò lẹ́nu iṣẹ́; ó pa Jóábù (26-35)

    • Wọ́n pa Ṣíméì (36-46)

  • 3

    • Sólómọ́nì fẹ́ ọmọ Fáráò (1-3)

    • Jèhófà fara han Sólómọ́nì lójú àlá (4-15)

      • Sólómọ́nì béèrè ọgbọ́n (7-9)

    • Sólómọ́nì dá ẹjọ́ láàárín àwọn ìyá méjì (16-28)

  • 4

    • Ìjọba Sólómọ́nì (1-19)

    • Àwọn èèyàn láásìkí nígbà àkóso Sólómọ́nì (20-28)

      • Àwọn èèyàn wà láàbò lábẹ́ àjàrà àti lábẹ́ igi ọ̀pọ̀tọ́ (25)

    • Ọgbọ́n Sólómọ́nì àti àwọn òwe rẹ̀ (29-34)

  • 5

    • Ọba Hírámù pèsè àwọn ohun èlò ìkọ́lé (1-12)

    • Àwọn tí Sólómọ́nì ní kó máa ṣiṣẹ́ fún òun (13-18)

  • 6

    • Sólómọ́nì kọ́ tẹ́ńpìlì (1-38)

      • Yàrá inú lọ́hùn-ún (19-22)

      • Àwọn kérúbù (23-28)

      • Àwọn ohun gbígbẹ́, àwọn ilẹ̀kùn, àgbàlá inú (29-36)

      • Iṣẹ́ kíkọ́ tẹ́ńpìlì parí ní nǹkan bí ọdún méje (37, 38)

  • 7

    • Ààfin Sólómọ́nì (1-12)

    • Hírámù tó jẹ́ akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ ran Sólómọ́nì lọ́wọ́ (13-47)

      • Àwọn òpó bàbà méjì (15-22)

      • Òkun tí a fi irin rọ (23-26)

      • Àwọn kẹ̀kẹ́ ẹrù mẹ́wàá àti àwọn bàsíà bàbà (27-39)

    • Wọ́n parí àwọn ohun èlò tí wọ́n fi wúrà ṣe (48-51)

  • 8

    • Wọ́n gbé Àpótí wọnú tẹ́ńpìlì (1-13)

    • Sólómọ́nì bá àwọn èèyàn sọ̀rọ̀ (14-21)

    • Àdúrà tí Sólómọ́nì fi ya tẹ́ńpìlì sí mímọ́ (22-53)

    • Sólómọ́nì súre fún àwọn èèyàn náà (54-61)

    • Àwọn ẹbọ àti àjọyọ̀ ìyàsímímọ́ (62-66)

  • 9

    • Jèhófà tún fara han Sólómọ́nì (1-9)

    • Ẹ̀bùn tí Sólómọ́nì fún Ọba Hírámù (10-14)

    • Oríṣiríṣi iṣẹ́ ìkọ́lé tí Sólómọ́nì ṣe (15-28)

  • 10

    • Ọbabìnrin Ṣébà ṣèbẹ̀wò sọ́dọ̀ Sólómọ́nì (1-13)

    • Ọrọ̀ rẹpẹtẹ tí Sólómọ́nì ní (14-29)

  • 11

    • Àwọn ìyàwó Sólómọ́nì yí i lọ́kàn pa dà (1-13)

    • Àwọn alátakò dìde sí Sólómọ́nì (14-25)

    • Ọlọ́run ṣèlérí ẹ̀yà mẹ́wàá fún Jèróbóámù (26-40)

    • Sólómọ́nì kú; wọ́n fi Rèhóbóámù jọba (41-43)

  • 12

    • Ìdáhùn líle tí Rèhóbóámù fún àwọn èèyàn (1-15)

    • Ẹ̀yà mẹ́wàá yapa (16-19)

    • Wọ́n fi Jèróbóámù jẹ ọba Ísírẹ́lì (20)

    • Ọlọ́run ní kí Rèhóbóámù má ṣe bá Ísírẹ́lì jà (21-24)

    • Ìjọsìn ère ọmọ màlúù tí Jèróbóámù gbé kalẹ̀ (25-33)

  • 13

    • Àsọtẹ́lẹ̀ sórí pẹpẹ tó wà ní Bẹ́tẹ́lì (1-10)

      • Pẹpẹ là sọ́tọ̀ọ̀tọ̀ (5)

    • Èèyàn Ọlọ́run ṣàìgbọràn (11-34)

  • 14

    • Àsọtẹ́lẹ̀ tí Áhíjà sọ sórí Jèróbóámù (1-20)

    • Rèhóbóámù ṣàkóso lórí Júdà (21-31)

      • Ṣíṣákì ya wọ Jerúsálẹ́mù (25, 26)

  • 15

    • Ábíjámú di ọba Júdà (1-8)

    • Ásà di ọba Júdà (9-24)

    • Nádábù di ọba Ísírẹ́lì (25-32)

    • Bááṣà di ọba Ísírẹ́lì (33, 34)

  • 16

    • Ìdájọ́ Jèhófà lórí Bááṣà (1-7)

    • Élà di ọba Ísírẹ́lì (8-14)

    • Símírì di ọba Ísírẹ́lì (15-20)

    • Ómírì di ọba Ísírẹ́lì (21-28)

    • Áhábù di ọba Ísírẹ́lì (29-33)

    • Híélì tún Jẹ́ríkò kọ́ (34)

  • 17

    • Wòlíì Èlíjà sọ tẹ́lẹ̀ pé ọ̀dá máa wà (1)

    • Àwọn ẹyẹ ìwò bọ́ Èlíjà (2-7)

    • Èlíjà dé sọ́dọ̀ opó kan ní Sáréfátì (8-16)

    • Ọmọ opó náà kú, ó sì jíǹde (17-24)

  • 18

    • Èlíjà pàdé Ọbadáyà àti Áhábù (1-18)

    • Èlíjà àti àwọn wòlíì Báálì ní Kámẹ́lì (19-40)

      • ‘Wọ́n ń ṣiyèméjì’ (21)

    • Ọ̀dá ọlọ́dún mẹ́ta àti ààbọ̀ dópin (41-46)

  • 19

    • Èlíjà sá lọ nítorí ìbínú Jésíbẹ́lì (1-8)

    • Jèhófà fara han Èlíjà ní Hórébù (9-14)

    • Ọlọ́run ní kí Èlíjà fòróró yan Hásáẹ́lì, Jéhù àti Èlíṣà (15-18)

    • Ọlọ́run yan Èlíṣà sí ipò Èlíjà (19-21)

  • 20

    • Àwọn ará Síríà gbógun ti Áhábù (1-12)

    • Áhábù ṣẹ́gun àwọn ará Síríà (13-34)

    • Àsọtẹ́lẹ̀ lórí Áhábù (35-43)

  • 21

    • Ọgbà àjàrà Nábótì wọ Áhábù lójú (1-4)

    • Jésíbẹ́lì fa ikú Nábótì (5-16)

    • Iṣẹ́ tí Èlíjà jẹ́ fún Áhábù (17-26)

    • Áhábù rẹ ara rẹ̀ sílẹ̀ (27-29)

  • 22

    • Àjọṣe Jèhóṣáfátì àti Áhábù (1-12)

    • Mikáyà sọ tẹ́lẹ̀ pé wọ́n máa ṣẹ́gun Áhábù (13-28)

      • Ẹ̀mí tó máa tan Áhábù (21, 22)

    • Wọ́n pa Áhábù ní Ramoti-gílíádì (29-40)

    • Jèhóṣáfátì ṣàkóso lórí Júdà (41-50)

    • Ahasáyà di ọba Ísírẹ́lì (51-53)