Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ìwé Émọ́sì

Orí

1 2 3 4 5 6 7 8 9

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

  • 1

    • Émọ́sì gba iṣẹ́ kan látọ̀dọ̀ Jèhófà (1, 2)

    • Ìdájọ́ lórí ìdìtẹ̀ tó ń wáyé (3-15)

  • 2

    • Ìdájọ́ lórí ìdìtẹ̀ tó ń wáyé (1-16)

      • Móábù (1-3), Júdà (4, 5), Ísírẹ́lì (6-16)

  • 3

    • Ìkéde ìdájọ́ Ọlọ́run (1-8)

      • Ọlọ́run ń fi àṣírí ọ̀rọ̀ rẹ̀ hàn (7)

    • Ohun tó máa ṣẹlẹ̀ sí Samáríà (9-15)

  • 4

    • Ohun tó máa ṣẹlẹ̀ sí àwọn abo màlúù Báṣánì (1-3)

    • Jèhófà kórìíra ìjọsìn èké Ísírẹ́lì (4, 5)

    • Ísírẹ́lì kò gba ìbáwí (6-13)

      • “Múra sílẹ̀ láti pàdé Ọlọ́run rẹ” (12)

      • ‘Ọlọ́run ń sọ èrò rẹ̀ fún àwọn èèyàn’ (13)

  • 5

    • Ísírẹ́lì dà bíi wúńdíá tó ṣubú (1-3)

    • Wá Ọlọ́run, kí o lè máa wà láàyè (4-17)

      • Kórìíra ohun búburú, nífẹ̀ẹ́ ohun rere (15)

    • Ọjọ́ Jèhófà máa jẹ́ ọjọ́ òkùnkùn (18-27)

      • Ọlọ́run kọ ẹbọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì (22)

  • 6

    • Ẹ gbé! Ẹ̀yin tí ẹ kò mikàn (1-14)

      • Ibùsùn tí wọ́n fi eyín erin ṣe; abọ́ wáìnì (4, 6)

  • 7

    • Ìran tó fi hàn pé òpin Ísírẹ́lì ti sún mọ́lé (1-9)

      • Eéṣú (1-3), iná (4-6), okùn ìwọ̀n (7-9)

    • Wọ́n ní kí Émọ́sì má sọ tẹ́lẹ̀ mọ́ (10-17)

  • 8

    • Ìran apẹ̀rẹ̀ tí èso ìgbà ẹ̀ẹ̀rùn wà nínú rẹ̀ (1-3)

    • Ọlọ́run dẹ́bi fún àwọn aninilára (4-14)

      • Ìyàn tẹ̀mí (11)

  • 9

    • Ìdájọ́ Ọlọ́run kò ṣeé yẹ̀ sílẹ̀ (1-10)

    • Ọlọ́run á gbé àtíbàbà Dáfídì dìde (11-15)