Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ìwé Ẹ́sírà

Orí

1 2 3 4 5 6 7 8 9 10

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

  • 1

    • Ọba Kírúsì pàṣẹ pé kí wọ́n tún tẹ́ńpìlì kọ́ (1-4)

    • Ètò tí wọ́n ṣe kí àwọn tó wà nígbèkùn ní Bábílónì lè pa dà (5-11)

  • 2

    • Orúkọ àwọn tó pa dà láti ìgbèkùn (1-67)

      • Àwọn ìránṣẹ́ tẹ́ńpìlì (43-54)

      • Àwọn ọmọ àwọn ìránṣẹ́ Sólómọ́nì (55-57)

    • Àwọn ọrẹ àtinúwá fún tẹ́ńpìlì (68-70)

  • 3

    • Wọ́n tún pẹpẹ kọ́, wọ́n sì rú àwọn ẹbọ (1-6)

    • Wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í tún tẹ́ńpìlì kọ́ (7-9)

    • Wọ́n fi ìpìlẹ̀ tẹ́ńpìlì lélẹ̀ (10-13)

  • 4

    • Wọ́n gbógun ti iṣẹ́ títún tẹ́ńpìlì kọ́ (1-6)

    • Àwọn ọ̀tá fi ìwé ẹ̀sùn ránṣẹ́ sí Ọba Atasásítà (7-16)

    • Ìdáhùn Atasásítà (17-22)

    • Iṣẹ́ kíkọ́ tẹ́ńpìlì dáwọ́ dúró (23-24)

  • 5

    • Àwọn Júù pa dà sẹ́nu kíkọ́ tẹ́ńpìlì (1-5)

    • Lẹ́tà tí Táténáì kọ sí Ọba Dáríúsì (6-17)

  • 6

    • Àyẹ̀wò tí Dáríúsì ṣe àti àṣẹ tó pa (1-12)

    • Wọ́n parí tẹ́ńpìlì, wọ́n sì ṣe ayẹyẹ ìṣílé (13-18)

    • Wọ́n ṣe Ìrékọjá (19-22)

  • 7

    • Ẹ́sírà wá sí Jerúsálẹ́mù (1-10)

    • Lẹ́tà tí Atasásítà kọ sí Ẹ́sírà (11-26)

    • Ẹ́sírà yin Jèhófà (27-28)

  • 8

    • Orúkọ àwọn tó tẹ̀ lé Ẹ́sírà pa dà (1-14)

    • Wọ́n múra ìrìn àjò náà (15-30)

    • Wọ́n kúrò ní Bábílónì, wọ́n dé sí Jerúsálẹ́mù (31-36)

  • 9

    • Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì àti àwọn ọmọ ilẹ̀ míì ń fẹ́ ara wọn (1-4)

    • Àdúrà ìjẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ tí Ẹ́sírà gbà (5-15)

  • 10

    • Wọ́n dá májẹ̀mú láti lé àwọn aya àjèjì lọ (1-14)

    • Wọ́n lé àwọn aya àjèjì lọ (15-44)