Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Iṣẹ́ àti Owó

Iṣẹ́

Ayé Dojú Rú​—Ṣe Ohun Tí Ò Ní Jẹ́ Kí Àtijẹ Àtimu Nira Fún Ẹ

To o ba mo beeyan se n sowo na, iyen o ni je ki nnkan nira ju fun e nigba isoro.

Ise Asekara—Se O si Niyi Lode Oni?

Awon kan ro pe ise asekara bu awon ku. Amo opo eeyan lo n gbadun ise asekara. Ki lo mu ki won gbadun ise won?

Ṣé Ọwọ́ Rẹ Máa Ń Dí Jù?

Ọ̀pọ̀ àwọn èèyàn ló máa ń sọ pé kì í rọrùn fún àwọn láti ṣe ojúṣe àwọn níbi iṣẹ́ àti nínú ilé. Kí ló fà á? Kí lèèyàn lè ṣe nípa rẹ̀?

Bí Owó Ti Ṣe Pàtàkì Tó

Ṣé Owó Ni Gbòǹgbò Ohun Búburú Gbogbo?

Àwọn èèyàn sábà máa ń sọ pé “owó ni gbòǹgbò ohun búburú gbogbo” àmọ́ kì í ṣe bí Bíbélì ṣe sọ ọ́ nìyẹn.

Bíbélì Lè Mú Kó O Túbọ̀ Mọ Béèyàn Ṣe Ń Gbọ́ Bùkátà

Báwo ni Bíbélì ṣe lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti dín ìṣòro owó kù?

Èrò Tó Yẹ Ká Ní Nípa Owó

Àwọn ìbéèrè méje wà tó o lè fi yẹ ara rẹ wò bóyá èrò tó yẹ ló ní nípa owó.

Ohun Tó Ń Fúnni Láyọ̀​—Ìtẹ́lọ́rùn àti Ìwà Ọ̀làwọ́

Ọ̀pọ̀ èèyàn ló gbà pé bí àwọ́n bá ṣe lówó tó ni àwọn ṣe máa láyọ̀ tó. Àmọ́ ṣé owó àti ohun ìní rẹpẹtẹ ló ń fúnni ní ojúlówó ayọ̀? Kí ni ẹ̀rí fi hàn?

Ṣó Dájú Pé Ọjọ́ Ọ̀la Ẹnì Kan Á Dáa Tó Bá Kàwé Dáadáa Tó Sì Lówó Rẹpẹtẹ?

Ọ̀pọ̀ èèyàn ló ti rí i pé bẹ́nì kan bá tiẹ̀ kàwé dáadáa tó sì lówó rẹpẹtẹ, ìyẹn ò sọ pé ọjọ́ ọ̀la ẹni náà á dáa.

Ṣé Ìgbà Kan Ń Bọ̀ Táwọn Olówó Àtàwọn Tálákà Máa Ní Nǹkan Lọ́gbọọgba?

Ìjọba kan wà tó lè pín nǹkan lọ́gbọọgba, kó sì mú ipò òṣì kúrò.

Ohun Mẹ́ta Tí Owó Kò Lè Rà

Owó máa ń jẹ́ ká lè ra àwọn nǹkan kan tá a nílò, àmọ́ owó ò lè ra àwọn ohun tó máa ń fún wa láyọ̀ jù.

Àníyàn Nípa Owó

Ọkùnrin kan pèsè fún ìdílé rẹ̀ nígbà tí owó ọjà di ọ̀wọ́n gógó.

Mo Rí Ọrọ̀ Tòótọ́

Báwo ni ọ̀gá oníṣòwò kan tó rí tajé ṣe ṣe rí ohun kan tó túbọ̀ níye lórí ju ọrọ̀ àti owó lọ?

Bó O Ṣe Lè Ṣọ́wó Ná

Bó O Ṣe Lè Máa Ṣọ́wó Ná

Lóòótọ́, nǹkan kì í bára dé téèyàn bá pàdánù iṣẹ́ tó ń mówó wọlé fún un, àmọ́ àwọn ọ̀rọ̀ ọgbọ́n tó wà nínú Bíbélì lè ṣèrànwọ́ kéèyàn lè mọ́ bá a ṣe máa ṣọ́ ìwọ̀nba owó tó wà lọ́wọ́ ná.

Ohun Táwọn Ọ̀dọ́ Sọ Nípa Owó

Kẹ́kọ̀ọ́ nípa bó o ṣe lè fowó pa mọ́, bó ṣe yẹ kó o ná an àti bó ò ṣe ní sọ ara rẹ di ẹrú owó.

Ǹjẹ́ Bíbélì Lè Ràn Mí Lọ́wọ́ Tí Mo Bá Ní Ìṣòro Owó Tàbí Ti Mo Bá Jẹ Gbèsè?

Ti pé èèyàn ní owó kò sọ pé kó ní ayọ̀, àmọ́ àwọn ìlànà Bíbélì mẹ́rin kan yóò ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti bójú tó ọ̀rọ̀ owó.

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Máa Ṣọ́ Owó Ná?

Ṣe o ti lọ sílé ìtajà rí pé kó o lọ wo ohun tí wọ́n ń tà níbẹ̀, àmọ́ tó jẹ́ pé nígbà tó o fi máa jáde níbẹ̀, o ti ra ọjà tó wọ́n gan-an? Tó bá ti ṣe ẹ rí, àpilẹ̀kọ yìí máa ràn ẹ́ lọ́wọ́.

Ìgbà Tó Yẹ Kó O Pa Dà Sọ́dọ̀ Àwọn Òbí Rẹ

Ṣé nǹkan ṣòro fún ẹ nígbà tó filé lẹ̀ láti lọ máa dá gbé? Àwọn ìmọ̀ràn yìí lè ràn ẹ́ lọ́wọ́.

Ohun Tí Ẹ Lè Ṣe Nípa Gbèsè

Kí ni ìdílé le ṣe tí wọ́n bá ti wọko gbèsè?

Bó O Ṣe Lè Fara Da Àìlówólọ́wọ́

Ohun Tí Bíbélì Sọ Nípa Ipò Òṣì

Ṣé àwọn òtòṣì lè láyọ̀?

Ǹjẹ́ Ìṣẹ́ àti Òṣì Lè Dópin Láyé?

Ta ló lè fòpin sí ìṣẹ́ àti òṣì?

Ǹjẹ́ Ọ̀rọ̀ Àwọn Aláìní Tiẹ̀ Jẹ Ọlọ́run Lógún?

Ka ohun tí Ọlọ́run ṣe láti fi han pé ọ̀rọ̀ àwọn aláìní jẹ òun lógún.

Ọ̀rọ̀ Pàtàkì Fún Àwọn Tó Fẹ́ Ṣí Lọ sí Ìlú Míì

Tó o bá kó lọ sí orílẹ̀-èdè míì, ṣe ìyẹn fi han pé ìdílé rẹ máa láyọ̀?