Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Bó O Ṣe Lè Fara Da Àjálù

Ìjìyà

Ohun Ti Bibeli So Nipa Iya

Se Olorun ri gbogbo iya ta a n je?

Tẹ́nì Kan Bá Ń Jìyà, Ṣé Ọlọ́run Ló Fà Á?

Ṣé Ọlọ́run máa ń fi àìsàn tàbí àjálù jẹ àwọn èèyàn níyà nítorí ẹ̀ṣẹ̀ wọn?

Kí Ni Mo Lè Ṣe Tí Àjálù Bá Dé Bá Mi?

Àwọn ọ̀dọ́ kan sọ ohun tó ràn wọ́n lọ́wọ́.

Ìdí Tó Fi Dá Wa Lójú Pé Ọ̀la Máa Dáa

Kí nìdí táwọn ìlérí tó wà nínú Bíbélì fi yàtọ̀ sáwọn ìlérí táwọn èèyàn máa ń ṣe?

Àwọn Ohun Àgbàyanu Tó Máa Ṣẹlẹ̀ Lọ́jọ́ Ọ̀la

Wàá rí bí Jésù ṣe máa sọ ayé di Párádísè.

Ìgbà Wo La Máa Bọ́ Lọ́wọ́ Àwọn Afẹ̀míṣòfò?

Títí dìgbà tá a máa bọ́ lọ́wọ́ àwọn oníwà ipá àtàwọn afẹ̀míṣòfò, Bíbélì sọ ohun méjì tá a lè ṣe láti fara dà á táwọn èèyànkéèyàn bá ṣọṣẹ́.

Kí Ló Yẹ Kí N Mọ̀ Nípa Ìfipá Báni Ṣèṣekúṣe?​—Apá 2: Bó O Ṣe Lè Kọ́fẹ Pa Dà

Ka nípa ohun tí àwọn tí wọ́n fipá bá ṣèṣekúṣe àmọ́ tí wọ́n ti kọ́fẹ pa dà sọ.

Ǹjẹ́ Ìyà Tó Ń Jẹ Wá Tiẹ̀ Kan Ọlọ́run?

Ọ̀pọ̀ èèyàn máa ń sọ pé kò sí Ọlọ́run torí ìyà tó ń jẹ wọ́n. Wo bí Bíbélì ṣe jẹ́ ká mọ bí ìyà tó ń jẹ wá ṣe rí lára Ọlọ́run.

Kí Nìdí Tí Ọlọ́run Fi Gbà Pé Ká Máa Jìyà?

Ọ̀pọ̀ èèyàn ló máa ń béèrè pé kí ló fà á tí ìkórìíra àti ìyà fi pọ̀ láyé. Bíbélì dáhùn ìbéèrè yìí lọ́nà tó tẹ́ni lọ́rùn tó sì tuni nínú.

Kí Nìdí Tí Ọlọ́run Ṣe Fàyè Gba Ìpakúpa Rẹpẹtẹ?

Ọ̀pọ̀ èèyàn tí béèrè ìdí tí Ọlọ́run onífẹ̀ẹ́ fi fàyè gba ìjìyà. Bíbélì fún wa ní ìdáhùn tó tẹ́rùn!

Ìyà Máa Dópin Láìpẹ́!

Ọlọ́run ti ṣèlérí pé òun má mú gbogbo ohun tó ń fa ìyà kúrò. Báwo ló ṣe máa ṣe é, ìgbà wo sì ni?

Ikú Èèyàn Ẹni

Tí Ẹni Tó O Fẹ́ràn Bá Kú

Wo fídíò yìí kó o lè mọ ohun tó o lè ṣe kára lè tù ẹ́ tó o bá ń ṣọ̀fọ̀.

Ohun Tó Lè Ran Àwọn Tó Ń Ṣọ̀fọ̀ Lọ́wọ́

Ọ̀pọ̀ èèyàn tó ń ṣọ̀fọ̀ ló ti rí ìrànlọ́wọ́ gbà torí pé wọ́n ṣe àwọn nǹkan tó yẹ.

Tí Ẹnì Kan Tó O Fẹ́ràn Bá Kú, Ṣé Ayé Rẹ Ṣì Lè Dùn?

Wo ohun márùn-⁠ún tó o lè ṣe tí ẹnì kan tó o fẹ́ràn bá kú.

Nígbà Tí Òbí Ẹnì Kan Bá Kú

Ohun tí kò bára dé ni kí èèyàn pàdánù òbí ẹ̀, ẹ̀dùn ọkàn náà kì í sì kúrò lọ́kàn bọ̀rọ̀. Kí ló lè ran àwọn ọmọdé lọ́wọ́ láti tètè gbé ìbànújẹ́ náà kúrò lọ́kàn?

Tí Òbí Ọmọdé Kan Bá Kú

Báwo ni Bíbélì ṣe ran àwọn ọmọ mẹ́ta kan lọ́wọ́ láti fara da ìbànújẹ́ tí ikú mọ̀lẹ́bí wọn fà?

Bi O Se Le Salaye Ohun Ti Iku Je fun Omo Re

Ohun merin to o le se lati dahun ibeere won, ta a si mu ki won fara da a ti eni ti won feran ba ku.

Bó Ṣe Lè Dá Ẹ Lójú Pé—Àjíǹde Àwọn Òkú Máa Wà?

Bíbélì fún wa ní ẹ̀rí méjì tó fẹsẹ̀ múlẹ̀ tó mú ká gbà pé àjíǹde dájú.

Ìrànlọ́wọ́ Tó Dára Jù Lọ fún Àwọn Tó Ń Ṣọ̀fọ̀

Bíbélì ló lè pèsè ìrànlọ́wọ́ tó dára jù lọ fún àwọn tó ń ṣọ̀fọ̀.

Àjálù

Ṣé Bíbélì Lè Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́ Láti Fara Da Àjálù Tí Ojú Ọjọ́ Máa Ń Fà?

Bíbélì lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti mọ ohun tó o máa ṣe kí àjálù tí ojú ọjọ́ máa ń fà tó ṣẹlẹ̀, tó bá ń ṣẹlẹ̀ lọ́wọ́ àti lẹ́yìn tó bá ṣẹlẹ̀.

Tí Àjálù Bá Ṣẹlẹ̀​—Ohun Tó O Lè Ṣe Láti Gbẹ̀mí Là

Àwọn àbá yìí lè gba ẹ̀mí ẹ àti tàwọn mí ì là.

Tí Àjálù Bá Ṣẹlẹ̀, Ṣé Ayé Rẹ Ṣì Lè Dùn?

Bíbélì jẹ́ ká mọ àwọn ohun tá a lè ṣe láti borí ẹ̀dùn ọkàn wa nígbà tí àjálù bá ṣẹlẹ̀.

Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Àwọn Àjálù Tó Ń Ṣẹlẹ̀?

Ṣé Ọlọ́run ló ń fi wọ́n jẹ wá níyà? Ṣé Ọlọ́run máa ń ṣèrànwọ́ fáwọn tí àjálù bá?

Ìgbàgbọ́ Wọn Ò Mì Nígbà Tí Ìjì Jà ní Philippines

Àwọn tó làá já sọ ohun tó ṣẹlẹ̀ nígbà tí ìjì líle tí wọ́n ń pè ní Super Typhoon Haiyan jà.