Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Ìyà

Kí Nìdí Tí ìyà Fi Pọ̀?

Ṣé Ọlọ́run Ló Fa Ìyà Tó Ń Jẹ Aráyé?

Ìpọ́njú lè bá ẹnikẹ́ni, títí kan àwọn tí Ọlọ́run ṣojú rere sí pàápàá. Kí nìdí?

Ṣé Èṣù Ló Ń Fa Gbogbo Ìjìyà?

Bíbélì jẹ́ ká mọ ohun tó fà á táwa èèyàn fi ń jìyà.

Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Àwọn Àjálù Tó Ń Ṣẹlẹ̀?

Ṣé Ọlọ́run ló ń fi wọ́n jẹ wá níyà? Ṣé Ọlọ́run máa ń ṣèrànwọ́ fáwọn tí àjálù bá?

Kí Ni Bíbélì Jẹ́ Ká Mọ̀ Nípa Àjàkálẹ̀ Àrùn?

Àwọn kan gbà pé Ọlọ́run ló ń fi àjàkálẹ̀ àrùn àti àìsàn tó ń ṣẹlẹ̀ lákòókò wa yìí jẹ àwọn èèyàn níyà. Àmọ́, ohun tí Bíbélì sọ kọ́ nìyẹn.

Kí Nìdí Tí Ọlọ́run Ṣe Fàyè Gba Ìpakúpa Rẹpẹtẹ?

Ọ̀pọ̀ èèyàn tí béèrè ìdí tí Ọlọ́run onífẹ̀ẹ́ fi fàyè gba ìjìyà. Bíbélì fún wa ní ìdáhùn tó tẹ́rùn!

Kí Nìdí Tí Kò Fi Sí Àlàáfíà Ní Ayé?

Gbogbo ìsapá àwọn èèyàn láti mú kí àlàáfíà wà ní ayé ti já sí pàbó. Gbé àwọn ohun tó fà á yẹ̀ wò.

Bó O Ṣe Lè Fara Da Ìyà

Ṣé Mo Lè Rí Àwọn Ọ̀rọ̀ Tó Máa Tù Mí Nínú Nínú Bíbélì?

Àwọn ẹsẹ Bíbélì tó ti tu àwọn tó ní ìṣòro àti ẹ̀dùn ọkàn nínú.

Ǹjẹ́ Bíbélì Lè Ràn Mí Lọ́wọ́ Tí Mo Bá Ní Ìrẹ̀wẹ̀sì Ọkàn?

Àwọn ohun mẹ́ta kan wà tí Ọlọ́run máa ń fún wa ká lè fara da ìrẹ̀wẹ̀sì ọkàn.

Báwo Ni Bíbélì Ṣe Lè Ran Àwọn Tó Ń Ronú Àtipa Ara Wọn Lọ́wọ́?

Àwọn ìmọ̀ràn wo nínú Bíbélì ló wúlò fún ẹni táyé ti sú?

Ǹjẹ́ Bíbélì Lè Ràn Mí Lọ́wọ́ Tí Mo Bá Ń Ṣàìsàn Ọlọ́jọ́ Pípẹ́?

Bẹ́ẹ̀ ni! Kọ́ nípa ohun mẹ́ta tó lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti fara da àìsàn ọlọ́jọ́ pípẹ́.

Kí ni Bíbélì Sọ Nípa Gbígba Ẹ̀mí Ẹnìkan Tó Ń Jẹ̀ Ìrora?

Ká sọ pé ẹnì kan ń ṣàìṣàn gbẹ̀mí-gbẹ̀mí ńkọ́? Ṣé pon dandan kí n ṣe gbogbo ohun tó bá gbà láti dá ẹ̀mí mi sí?

Ìyà Máa Dópin

Kí Ni Ìjọba Ọlọ́run Máa Ṣe?

Kọ́ nípa ohun tó máa wáyé nígbà tí Ìjọba Ọlọ́run bá ń ṣàkóso gbogbo aye.

Kí Ló Lè Fún Mi Ní Ìrètí?

Orísun ìrètí tó ṣeé gbára lé máa jẹ́ kí ayé rẹ dára sí i nísinsìnyìí, ó sì máa jẹ́ kí ọjọ́ ọ̀la rẹ dájú.