Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Ibi Tí Àwọn Ẹni Ẹ̀mí Ń Gbé

Ọ̀run

Ibo Là Ń Pè Ní Ọ̀run?

Bí Bíbélì ṣe lò o, ohun mẹ́ta ni ọ̀rọ̀ náà túmọ̀ sí.

Àwọn Wo Ló Ń Lọ sí Ọ̀run?

Ọ̀pọ̀ èèyàn ló gbà pé gbogbo èèyàn rere ló ń lọ sọ́run. Kí ni Bíbélì fi kọ́ni gan-an?

Kí Ni Jerúsálẹ́mù Tuntun?

Báwo ni ọ̀rọ̀ ìlú tó ṣàrà ọ̀tọ̀ yìí ṣe kàn ọ́?

Ǹjẹ́ Ibì Kan Wà Tí Ọlọ́run Ń Gbé?

Kí ni Bíbélì sọ nípa ibi tí Ọlọ́run ń gbé? Ṣé ibi kan náà ní Jésù ń gbé?

Áńgẹ́lì

Àwọn Wo Là Ń Pè Ní Áńgẹ́lì?

Mélòó ni wọ́n? Ṣé gbogbo wọn ló yàtọ̀ síra, tí kálukú wọn sì ní orúkọ ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀?

Ta Ni Máíkẹ́lì, Olú-Áńgẹ́lì?

Ó tún ní orúkọ míì tó ṣeé ṣe kó jẹ́ òun lo mọ̀ dáadáa.

Èṣù Àtàwọn Ẹ̀mí Èṣù

Ǹjẹ́ Èṣù Wà?

Ǹjẹ́ èrò ibi tó wà nínú èèyàn tàbí ìwà ibi téèyàn hù ni Èṣù tàbí ẹni gidi kan ni?

Ṣé Ọlọ́run Ló Dá Èṣù?

Ohun tí Bíbélì sọ bọ́gbọ́n mu, ó sì tuni lára.

Báwo Ni Èṣù Ṣe Rí?

Ṣé Bíbélì sọ ìrísí èṣù nígbà tó ń fi í wé dírágónì tàbí kìnnìún?

Ibo Ni Èṣù Ń Gbé?

Bíbélì sọ pé wọ́n lé Èṣù kúrò ní ọ̀run. Ibo ni Sátánì wà báyìí?

Ǹjẹ́ Èṣù Lè Darí Àwọn Èèyàn?

Báwo ni Èṣù ṣe ń nípa lórí àwọn èèyàn àti pé báwo ni a ṣe lè dènà àwọn àrékérekè rẹ̀?

Ṣé Èṣù Ló Ń Fa Gbogbo Ìjìyà?

Bíbélì jẹ́ ká mọ ohun tó fà á táwa èèyàn fi ń jìyà.

Ǹjẹ́ Àwọn Ẹ̀mí Èṣù Wà?

Àwọn wo ni ẹ̀mí èṣù? Ibo ni wọ́n ti wá?

Àwọn Wo Làwọn Néfílímù?

Bíbélì pè wọ́n ní àwọn “alágbára ńlá tí wọ́n wà ní ìgbà láéláé, àwọn ọkùnrin olókìkí.” Kí la mọ̀ nípa wọn?