Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Ukraine

 

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ní Orílẹ̀-èdè Ukraine

  • Iye àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà​—109,375

  • Iye àwọn ìjọ​—1,234

  • Iye àwọn tó wá síbi Ìrántí Ikú Kristi​—185,910

  • Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún​—391

  • Iye èèyàn​—41,130,000

2019-09-23

UKRAINE

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Lórílẹ̀-Èdè Ukraine Ṣàfihàn Bíbélì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà lórílẹ̀-èdè Ukraine ṣe àfihàn kan tó ṣàrà ọ̀tọ̀ nípa Ìwé Mímọ́ Kristẹni Lédè Gíríìkì ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun tá a mú jáde ní Èdè Adití ti Rọ́síà.

2019-01-15

UKRAINE

Ìṣọ̀kan àti Aájò Àlejò Wà Láàárín Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Nígbà Àkànṣe Àpéjọ ní Ukraine

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó wà ní ìlú Lviv, lórílẹ̀-èdè Ukraine, kí ẹgbẹẹgbẹ̀rún èèyàn tó wá káàbọ̀ síbi àkànṣe àpéjọ náà. Àwọn tó wá rí oríṣiríṣi àṣà ìbílẹ̀, wọ́n sì mú wọn rìn káàkiri.

2019-01-15

UKRAINE

Wọ́n Fòfin De Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ní “Donetsk People’s Republic”

Ìfòfindè tí Ilé Ẹjọ́ Gíga Jù Lọ ní DPR ṣe yìí ni ìgbésẹ̀ tuntun tí wọ́n gbé nínú bí wọ́n ṣe ń ṣe inúnibíni sí àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ní ìlà oòrùn ilẹ̀ Ukraine torí ẹ̀sìn wọn.

2018-04-23

UKRAINE

Òmìnira Ẹ̀sìn Wà Nínú Ewu Láwọn Àgbègbè Kan ní Ìlà Oòrùn Orílẹ̀-èdè Ukraine

Wọ́n ń halẹ̀ mọ́ àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà, wọn ò sì jẹ́ kí wọ́n lómìnira ẹ̀sìn láwọn àgbègbè kan ní Luhansk àti Donetsk.

2017-08-29

UKRAINE

Àwọn Aláṣẹ Wá Wo Ẹ̀ka Ọ́fíìsì Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Lórílẹ̀-èdè Ukraine

Látọdún 2001, May 2, 2017 ni ìgbà àkọ́kọ́ táwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà máa ṣètò lákànṣe láti ṣí ẹ̀ka ọ́fíìsì wa tó wà lórílẹ̀-èdè Ukraine sílẹ̀ káwọn èèyàn lè wá wò ó.

2017-04-07

UKRAINE

Ilé Ẹjọ́ Gíga ní Ukraine Túbọ̀ Jẹ́ Kí Àwọn Aráàlú Lómìnira Láti Máa Kóra Jọ ní Àlàáfíà

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó wà ní Ukraine ti lè máa pàdé fún ìjọsìn báyìí láìsí ìdíwọ́ nínú ilé tí wọ́n bá yá.

2017-01-19

UKRAINE

Wọn Ò Yéé Dí Ìjọsìn Lọ́wọ́ ní Apá Ìlà Oòrùn Orílẹ̀-èdè Ukraine

Àwọn ológun ṣì ń fipá gba Gbọ̀ngàn Ìjọba. Láìka gbogbo ìṣòro yìí sí, àwọn Ẹlẹ́rìí ń pàdé pọ̀ pẹ̀lú àwọn ará wọn kí wọ́n lè jọ jọ́sìn.

2016-05-04

UKRAINE

Ìdájọ́ Òdodo Borí Nílẹ̀ Ukraine

Ilé Ẹjọ́ Gíga Jù Lọ Nílẹ̀ Ukraine fagi lé ìgbìyànjú àwọn kan tí wọ́n fẹ́ gba ilẹ̀ àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà.