Iṣẹ́ Ìtẹ̀wé Wa

ÀKÓJỌ ÀPILẸ̀KỌ ÀTI FÍDÍÒ

Bíbélì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun tá a tún ṣe ti wà lédè Spanish

Lédè Spanish ọ̀rọ̀ kan lè ní ìtumọ̀ oríṣiríṣi, báwo làwọn tó túmọ̀ Bíbélì náà ṣe ṣeé?

ÀKÓJỌ ÀPILẸ̀KỌ ÀTI FÍDÍÒ

Bíbélì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun tá a tún ṣe ti wà lédè Spanish

Lédè Spanish ọ̀rọ̀ kan lè ní ìtumọ̀ oríṣiríṣi, báwo làwọn tó túmọ̀ Bíbélì náà ṣe ṣeé?

Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Mú Kí Wọ́n Láyọ̀

A mú ìwé Mátíù jáde ní èdè adití ti Japan. Ẹ wo bó ti dùn tó pé a ní Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run tá a tú sí èdè tó wọ àwọn arákùnrin àti arábìnrin tó jẹ́ adití lọ́kàn.

“Gbára Dì Pátápátá fún Gbogbo Iṣẹ́ Rere”!

Bíbélì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun rọrùn láti kà, síbẹ̀ wọ́n túmọ̀ rẹ̀ lọ́nà tó péye. Lára àwọn nǹkan tuntun tó wa nínú rẹ̀ ni àwòrán ilẹ̀ tó ní àwọ̀ mèremère, àlàyé ọ̀rọ̀ inú Bíbélì àtàwọn àfikún.

Wọ́n Ń Gbọ́ Ìhìn Rere ní Agbègbè Andes

Àwọn tó ń sọ èdè Quechua ní orílẹ̀-èdè Peru túbọ̀ sún mọ́ Jèhófà bí wọ́n ṣe ń ka àwọn ìwé wa àti Bíbélì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun lédè ìbílẹ̀ wọn.

Wọ́n Ń Túmọ̀ Èdè Láìkọ Ọ́ Sílẹ̀

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ti túmọ̀ àwọn ìtẹ̀jáde tó dá lórí Bíbélì sí èdè àwọn adití tó lé ní àádọ́rùn-ún, wọ́n ń sọ ọ̀rọ̀ orí ìwé di fídíò. Kí ló jẹ́ kí wọ́n máa sapá tó tóyìí?

Ó “Dáa Ju Àwọn Sinimá Àgbéléwò Lọ”

Báwo ni àwọn fídíò táwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà máa ń ṣe jáde láwọn àpéjọ àgbègbè wọn lọ́dọọdún ṣe máa ń rí lára àwọn èèyàn tó wá síbẹ̀? Báwo ni wọ́n ṣe ń ṣe àwọn fídíò yìí lóríṣiríṣi èdè tó pọ̀ gan-an?

A Túmọ̀ Ìtẹ̀jáde Sí Èdè Àwọn Adití Lọ́nà ti Quebec

Kí nìdí tó fi ṣe pàtàkì kí wọ́n túmọ̀ àwọn ìtẹ̀jáde sí èdè àwọn adití?

A Nífẹ̀ẹ́ Òtítọ́, A sì Ní Ọ̀wọ̀ Tó Jinlẹ̀ fún Òtítọ́

Ẹnikẹ́ni tó bá ka àwọn ìwé wa tàbí tó wo àwọn fídíò tó wà lórí ìkànnì wa lè fọkàn balẹ̀ torí a fara balẹ̀ ṣe ìwádìí lórí wọn, wọ́n sì jẹ́ òótọ́.

Bá A Ṣe Ń Ya Àwọn Àwòrán Tó Gbé Kókó Ọ̀rọ̀ Jáde

Báwo ni àwọn ayàwòrán wa ṣe ń ya àwọn àwòrán tó fani mọ́ra, tó sì bá kókó ọ̀rọ̀ inú àwọn ìtẹ̀jáde wa mu?

Àwọn Èèyàn Orílẹ̀-Èdè Estonia Mọyì “Iṣẹ́ Ńlá” Tá A Ṣe

Bíbélì Ìtúmọ̀ Ayé Tuntun wà lára àwọn ìwé tó fakọ yọ jù lọ tí wọ́n mú, tí wọ́n sì fún ní Àmì Ẹ̀yẹ Ìwé Tó Dára Jù Lọ ní Orílẹ̀-Èdè Estonia lọ́dún 2014.

Wọ́n Pín Ìwé Tó Ṣàlàyé Bíbélì Lórílẹ̀-Èdè Congo

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà yọ̀ǹda ara wa lóṣooṣù láti kó Bíbélì àtàwọn ìwé tó ṣàlàyé Bíbélì lọ fún àwọn èèyàn ní Orílẹ̀-èdè Congo.

Bíbélì Àtẹ́tísí Tó Wà fún Gbogbo Èèyàn

Onírúurú ohùn la gbà sílẹ̀ nínú àtẹ́tísí Bíbélì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun tí a tún ṣe lọ́dún 2013 ní èdè Gẹ̀ẹ́sì.

Orin Ìyìn sí Ọlọ́run Lónírúurú Èdè

Kà nípa àwọn ìṣòro tó wà nínú títú orin sí onírúurú èdè.

Ojú Ìwé Rẹ̀ Ò Pọ̀, Ó sì Wà ní Ọ̀pọ̀ Èdè

Bẹ̀rẹ̀ láti January 2013, a máa dín ojú ìwé àwọn ìwé ìròyìn Ilé Ìṣọ́ àti Jí! kù. Kí nìdí?

Fídíò Kékeré: “Ọpẹ́lọpẹ́ Rẹ̀ Lára Mi”

Wo fídíò yìí tó dá lórí ọkùnrin afọ́jú kan tó jàǹfààní nínú Bíbélì tí wọ́n ṣe fún àwọn afọ́jú.

A Fi Iṣẹ́ Títúmọ̀ “Àwọn Ọ̀rọ̀ Ìkéde Ọlọ́wọ̀ Ti Ọlọ́run” Síkàáwọ́ Wọn—Róòmù 3:2

Láti ọ̀pọ̀ ọdún títí di báyìí, àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ti fi ọ̀pọ̀ Bíbélì kọ́ àwọn èèyàn lẹ́kọ̀ọ́ òtítọ́. Kí nìdí tí wọ́n fi ṣe ìtúmọ̀ Bíbélì sí èdè Gẹ̀ẹ́sì òde òní?

Wọ́n Wá Kọrin

Ogójì ọdún sẹ́yìn làwọn arákùnrin àtàwọn arábìnrin ti ń wá láti ibi ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ lágbàáyé kí wọ́n lè kọ orin tá ó máa lò fún ìjọsìn wa àtàwọn fídíò tá à ń ṣe jáde.