Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

APRIL 22, 2022
ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2022 #3

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2022 #3

Ọ̀kan lára Ìgbìmọ̀ Olùdarí jẹ́ ká mọ bí nǹkan ṣe rí lára àwọn ará wa nígbà tí wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í ṣèpàdé lójúkojú. Ó tún jẹ́ ká mọ àwọn nǹkan tá a lè ṣe tá ò fi ní máa kọ́kàn sókè torí ogun tó ń jà lápá ìlà oòrùn Yúróòpù.