Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

OCTOBER 28, 2022
ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2022 #7

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2022 #7

Ọ̀kan lára Ìgbìmọ̀ Olùdarí jẹ́ ká mọ àwọn nǹkan tó ti ṣẹlẹ̀ látìgbà tá a tún ti bẹ̀rẹ̀ sí í wàásù tá a sì ń ṣèpàdé lójúkojú àtàwọn ètò ìrànwọ́ tá a ṣe láwọn ibi tí àjálù ti ṣẹlẹ̀. Wọ́n tún jẹ́ ká mọ ìdí tí kò fi yẹ ká máa fi nǹkan falẹ̀ nígbà tí ewu bá ń rọ̀ dẹ̀dẹ̀ lágbègbè tá a wà.