Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Turkey

  • Istanbul, Turkey​—Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan ń fi ìwé ìròyìn Jí! lọni ní èdè Turkey

Ìsọfúnni Ṣókí—Turkey

  • 85,957,000—Iye àwọn èèyàn
  • 5,692—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 71—Iye àwọn ìjọ
  • 15,502—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn Tinútinú​​—Ní Tọ́kì

Lọ́dún 2014, wọ́n ṣe àkànṣe ìwàásù kan ní Tọ́kì. Kí nìdí tí wọ́n fi ṣe àkànṣe ìwàásù náà? Kí ló sì yọrí sí?