Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Palestinian Territories

Ìsọfúnni Ṣókí—Palestinian Territories

  • 5,490,000—Iye àwọn èèyàn
  • 78—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 2—Iye àwọn ìjọ
  • 72,237—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ

Ìgbà Wo Ni Ìfẹ́ Tí Kì Í Yẹ̀ Máa Ṣẹ́gun Ìkórìíra?

Kò rọrùn láti fa ẹ̀tanú tu kúrò lọ́kàn. Wo bí Júù kan àti ará Palẹ́sínì kan ṣe ṣàṣeyọrí.

ÌRÒYÌN

Wọ́n Ń Fi Ẹ̀tọ́ Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Tó Wà ní Àgbègbè Palẹ́sínì Dù Wọ́n

Wọn ò gbà láti forúkọ ẹ̀sìn àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà sílẹ̀ lábẹ́ òfin torí wọn ò ka ẹ̀sìn wọn sí, ìyẹn wá ń jẹ́ kí wọ́n máa fi ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn tí wọ́n ní dù wọ́n, kò sì yẹ kó rí bẹ́ẹ̀.