Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ

Ìgbà Wo Ni Ìfẹ́ Tí Kì Í Yẹ̀ Máa Ṣẹ́gun Ìkórìíra?

Ìgbà Wo Ni Ìfẹ́ Tí Kì Í Yẹ̀ Máa Ṣẹ́gun Ìkórìíra?

 Ọjọ́ pẹ́ táwọn Júù àtàwọn ará Palẹ́sínì ti kórìíra ara wọn, síbẹ̀ a ti rí lára wọn tó ti fa ẹ̀tanú tu kúrò lọ́kàn, tí wọ́n sì ti kọ́ láti nífẹ̀ẹ́ àwọn tí wọ́n kà sí ọ̀tá tẹ́lẹ̀. Gbọ́rọ̀ látẹnu méjì lára wọn.