Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Korea, Republic of

  • Samcheong-dong, Seoul, South Korea—Wọ́n ń kọ́ni látinú Bíbélì

  • Daraengi Village, Namhae-do Island, South Korea​—Wọ́n ń fi ìwé pẹlẹbẹ Tẹ́tí sí Ọlọ́run lọni

  • Nonsan-si, Chungnam, South Korea​—Wọ́n ń wàásù fún ẹnì kan tó ń bu oúnjẹ níbi tí wọ́n ń kó oúnjẹ sí

Ìsọfúnni Ṣókí—Korea, Republic of

  • 51,408,000—Iye àwọn èèyàn
  • 106,161—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 1,252—Iye àwọn ìjọ
  • 485—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

ÌRÒYÌN

Àwọn Ará ní South Korea Ní Ìgbàgbọ́ àti Ìgboyà​—⁠Wọ́n Kọ̀ Láti Wọṣẹ́ Ológun

Látọdún 1953 ni ìjọba orílẹ̀-èdè Korea ti ń fi àwọn ọ̀dọ́kùnrin tó jẹ́ Ẹlẹ́rìí Jèhófà sẹ́wọ̀n torí wọ́n kọ̀ láti wọṣẹ́ ológun. Àmọ́, èyí yí pa dà ní February 2019. Kọ́ nípa bí ọ̀rọ̀ ṣe wá dé ibi tó dé yìí.

ÌRÒYÌN

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ṣe Àjọyọ̀ Ọgọ́rùn-ún Ọdún ní Korea

SEOUL, Korea—Oṣù pàtàkì ni November ọdún 2012 jẹ́ fún àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó lé ní ọ̀kẹ́ márùn-ún [100,000] ní orílẹ̀-èdè South Korea, torí oṣù náà ló pé ọgọ́rùn-ún ọdún tí àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ti wà lórílẹ̀-èdè náà.