Ìsọfúnni Ṣókí—Estonia
- 1,366,000—Iye àwọn èèyàn
- 4,110—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
- 54—Iye àwọn ìjọ
- 335—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún
IṢẸ́ ÌTẸ̀WÉ
Àwọn Èèyàn Orílẹ̀-Èdè Estonia Mọyì “Iṣẹ́ Ńlá” Tá A Ṣe
Bíbélì Ìtúmọ̀ Ayé Tuntun wà lára àwọn ìwé tó fakọ yọ jù lọ tí wọ́n mú, tí wọ́n sì fún ní Àmì Ẹ̀yẹ Ìwé Tó Dára Jù Lọ ní Orílẹ̀-Èdè Estonia lọ́dún 2014.
ILÉ ÌṢỌ́
“Ohun Tó Ti Ṣẹlẹ̀ Ti Ṣẹlẹ̀ Àmọ Ẹ Fi Ṣàríkọ́gbọ́n”
Ní April 1, 1951, Ọgọ́ọ̀rọ̀rún Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ni wọ́n lé kúrò nílùú Estonia lọ sí Siberia. Kí nìdí?