Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Argentina

  • Catamarca, Argentina​—Ẹlẹ́rìí kan ń ka Bíbélì fún darandaran kan nítòsí abúlé Alumbrera

Ìsọfúnni Ṣókí—Argentina

  • 46,045,000—Iye àwọn èèyàn
  • 153,751—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 1,938—Iye àwọn ìjọ
  • 301—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

ÌRÒYÌN

A Wàásù Lákànṣe Níbi Térò Pọ̀ sí Nígbà Eré Ìdárayá Òlíńpíìkì Tó Wáyé ní Ajẹntínà Lọ́dún 2018

Nǹkan bí ọgọ́rùn-ún méje ó lé àádọ́rùn-ún (790) ìwé làwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà pín lójoojúmọ́ nígbà ìwàásù àkànṣe náà kí àwọn eléré ìdárayá àtàwọn àlejò lè mọ̀ nípa ẹ̀kọ́ Bíbélì.