Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Ajẹntínà

 

2019-01-15

AJẸNTÍNÀ

A Wàásù Lákànṣe Níbi Térò Pọ̀ sí Nígbà Eré Ìdárayá Òlíńpíìkì Tó Wáyé ní Ajẹntínà Lọ́dún 2018

Nǹkan bí ọgọ́rùn-ún méje ó lé àádọ́rùn-ún (790) ìwé làwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà pín lójoojúmọ́ nígbà ìwàásù àkànṣe náà kí àwọn eléré ìdárayá àtàwọn àlejò lè mọ̀ nípa ẹ̀kọ́ Bíbélì.

2017-07-04

AJẸNTÍNÀ

Òjò Àrọ̀ọ̀rọ̀dá Rọ̀ ní Ajẹntínà, Ó sì Ba Ọ̀pọ̀ Nǹkan Jẹ́

Nínú àjálù tó wáyé ní àgbègbè mẹ́tàlá lórílẹ̀-èdè Ajẹntínà, ìkankan nínú àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ò kú, wọn ò sì fara pa.