Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ

Ọ̀pọ̀ Nǹkan Ni Jèhófà Ti Ṣe fún Mi

Ọ̀pọ̀ Nǹkan Ni Jèhófà Ti Ṣe fún Mi

 Obìnrin kan tó ń jẹ́ Crystal, tí ẹnì kan fipá bá lòpọ̀ nígbà tó wà ní kékeré sọ bí ẹ̀kọ́ Bíbélì tó kọ́ ṣe jẹ́ kó ní àjọṣe tó dán mọ́rán pẹ̀lú Jèhófà Ọlọ́run, tó sì jẹ́ kí ìgbésí ayé rẹ̀ nítumọ̀.