ÌWÉ ÀJÁKỌ Bó Ò Ṣe Ní Jẹ́ Kí Eré Ìdárayá Pa Ojúṣe Rẹ Lára TẸ̀ Ẹ̣́ Ìwé yìí máa ràn ẹ́ lọ́wọ́ kí eré ìdárayá tó o bá fẹ́ ṣe má bàa pa ojúṣe rẹ lára. Wà á jáde Àwọn Àkòrí Tó Jọ Ọ́ ìwé àjákọ Ọ̀dọ́ O Tún Lè Wo ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ Kí Ló Yẹ Kí N Mọ̀ Nípa Eré Ìdárayá? Ṣàyẹ̀wò irú eré tó ò ń ṣe, bó o ṣe ń ṣe é àti bí àkókò tó o fi ń ṣe eré ọ̀hún bá ṣe pọ̀ tó. ÀWỌN ERÉ OJÚ PÁTÁKÓ Kí Ni Géèmù Tó Ò Ń Gbá Ń Sọ Nípa Ẹ? Géèmù máa ń dùn ún gbá, àmọ́ kò ṣàìní ìpalára tó lè ṣe fúnni. Báwo lo ṣe lè yẹra fún ewu tó wà níbẹ̀ kó o sì máa gbádùn géèmù tó ò ń gbá? ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ Kí Ló Yẹ Kí N Mọ̀ Nípa Àwọn Géèmù orí Kọ̀ǹpútà? O lè má tíì ronú nípa àǹfààní tó lè ṣe ẹ́ àti àkóbá tó lè ṣe fún ẹ. OHUN TÁWỌN OJÚGBÀ RẸ SỌ Ohun Táwọn Ojúgbà Rẹ Sọ Nípa Fífi Nǹkan Falẹ̀ Gbọ́ ohun táwọn ọ̀dọ́ sọ nípa ewu tó wà nínú kéèyàn máa fi nǹkan falẹ̀ àti àǹfààní tó wà nínú kéèyàn máa jára mọ́ ohun tó ní í ṣe. Fi ránṣẹ́ Fi ránṣẹ́ Bó Ò Ṣe Ní Jẹ́ Kí Eré Ìdárayá Pa Ojúṣe Rẹ Lára ÌWÉ ÀJÁKỌ FÚN ÀWỌN Ọ̀DỌ́ Bó Ò Ṣe Ní Jẹ́ Kí Eré Ìdárayá Pa Ojúṣe Rẹ Lára Yorùbá Bó Ò Ṣe Ní Jẹ́ Kí Eré Ìdárayá Pa Ojúṣe Rẹ Lára https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/502016142/univ/art/502016142_univ_sqr_xl.jpg