Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

ERÉ ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ BÍBÉLÌ

Ọlọ́run Wo Hesekáyà Sàn

Kẹ́kọ̀ọ́ nípa bí Ọlọ́run ṣe mú kí ohun ìyanu kan ṣẹlẹ̀ sí Hesekáyà, tó sì dáhùn àdúrà rẹ̀. Wa ẹ̀kọ́ yìí jáde, ka ìtàn Bíbélì tó wà níbẹ̀, kó o sì máa fojú inú wò ó bí ohun tó ń ṣẹlẹ̀ lọ́wọ́lọ́wọ́!