Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

ERÉ ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ BÍBÉLÌ

Ọlọ́run Dáhùn Àdúrà Rẹ̀

Kẹ́kọ̀ọ́ nípa Nehemáyà, ọkùnrin tó gbàdúrà pé kí Ọlọ́run ran òun lọ́wọ́. Wa ẹ̀kọ́ yìí jáde, ka ìtàn Bíbélì tó wà níbẹ̀, kó o sì máa fojú inú wò ó bí ohun tó ń ṣẹlẹ̀ lọ́wọ́lọ́wọ́!