Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

ÀWỌN ERÉ OJÚ PÁTÁKÓ

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Yẹra fún Òfófó?

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Yẹra fún Òfófó?

Ó kàn lè jẹ́ pé ṣe lẹ ń tàkurọ̀sọ, àmọ́ ká tó o ṣẹ́jú pẹ́ẹ́, ọ̀rọ̀ náà lè di òfófó. Kí lo lè ṣe tó ò fi ní bá wọn dá sí i?