Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Bí Bíbélì Ṣe Bá Ìmọ̀ Sáyẹ́ǹsì Mu

Ṣe Òótọ́ Ni Ọ̀rọ̀ Inú Bíbélì?

Tó bá jẹ́ pé Ọlọ́run ló ni Bíbélì, á jẹ́ pé kò sí ìwé míì tá a lè fi í wé.

Ṣé Ìmọ̀ Sáyẹ́ǹsì Bá Ohun Tí Bíbélì Sọ Mu?

Ṣé àwọn ohun tí kì í ṣe òótọ́ nínú ìmọ̀ sáyẹ́ǹsì wà nínú Bíbélì?

Ìgbà Wo Ni Ọlọ́run Bẹ̀rẹ̀ Sí Í Dá Àgbáálá Ayé?

Tá a bá mọ bí Jẹ́nẹ́sísì ṣe lo àwọn ọ̀rọ̀ náà “ìbẹ̀rẹ̀” àti “ọjọ́” lá to lè dáhùn.

Ṣé Bíbélì Bá Àkókò Wa Mu? Àbí Kò Wúlò Mọ́ Rárá?

Bíbélì kì í ṣe ìwé sáyẹ́ǹsì, àmọ́ ohun tó sọ nípa sáyẹ́ǹsì máa yà ẹ́ lẹ́nu.

Àǹfààní Tí Ìmọ̀ Sáyẹ́ǹsì Ń Ṣe fún Wa

Kí nìdí táwọn kan fi sọ pé “ìmọ̀ sáyẹ́ǹsì fi hàn dájú pé kò sí Ọlọ́run”?

Ṣé Bíbélì Fi Kọ́ni Pé Ayé Rí Pẹrẹsẹ?

Ṣé ọ̀rọ̀ inú ìwé tó ti pẹ́ yìí péye?

Ignaz Semmelweis

Gbogbo ìdílé lónìí ló yẹ kó máa dúpẹ́ lọ́wọ́ ọkùnrin yìí. Kí nìdí?

Aristotle

Ọ̀pọ̀ lára ẹ̀kọ́ àwọn onímọ̀ ìjìnlẹ̀ ló pọ̀ jù lára ẹ̀kọ́ táwọn ẹlẹ́kọ̀ọ́ ìsìn ayé àtijọ́ fi ń kọ́ni.

Àwọn Òfin Ọlọ́run Lórí Ìmọ́tótó Là Wọ́n Lójú Gan-an

Orílẹ̀-èdè Ísírẹ́lì àtijọ́ jàǹfààní gan-an bí wọ́n ṣe ń pa àwọn òfin gíga Ọlọ́run mọ́ lórí ọ̀rọ̀ ìmọ́tótó.