Bó O Ṣe Lè Wá Ẹsẹ Ìwé Mímọ́ Nínú Bíbélì Rẹ
Àwọn Ìwé Inú Bíbélì a
Orúkọ Ìwé |
Òǹkọ̀wé |
Ìgbà Tí Wọ́n Kọ Ọ́ Tán |
---|---|---|
Mósè |
1513 Ṣ.S.K. |
|
Mósè |
1512 Ṣ.S.K. |
|
Mósè |
1512 Ṣ.S.K. |
|
Mósè |
1473 Ṣ.S.K. |
|
Mósè |
1473 Ṣ.S.K. |
|
Jóṣúà |
n. 1450 Ṣ.S.K. |
|
Sámúẹ́lì |
n. 1100 Ṣ.S.K. |
|
Sámúẹ́lì |
n. 1090 Ṣ.S.K. |
|
Sámúẹ́lì; Gádì; Nátánì |
n. 1078 Ṣ.S.K. |
|
Gádì; Nátánì |
n. 1040 Ṣ.S.K. |
|
Jeremáyà |
580 Ṣ.S.K. |
|
Jeremáyà |
580 Ṣ.S.K. |
|
Ẹ́sírà |
n. 460 Ṣ.S.K. |
|
Ẹ́sírà |
n. 460 Ṣ.S.K. |
|
Ẹ́sírà |
n. 460 Ṣ.S.K. |
|
Nehemáyà |
n. 443 Ṣ.S.K. |
|
Mọ́dékáì |
n. 475 Ṣ.S.K. |
|
Mósè |
n. 1473 Ṣ.S.K. |
|
Dáfídì àtàwọn míì |
n. 460 Ṣ.S.K. |
|
Sólómọ́nì; Ágúrì; Lémúẹ́lì |
n. 717 Ṣ.S.K. |
|
Sólómọ́nì |
ṣ. 1000 Ṣ.S.K. |
|
Sólómọ́nì |
n. 1020 Ṣ.S.K. |
|
Aísáyà |
l. 732 Ṣ.S.K. |
|
Jeremáyà |
580 Ṣ.S.K. |
|
Jeremáyà |
607 Ṣ.S.K. |
|
Ìsíkíẹ́lì |
n. 591 Ṣ.S.K. |
|
Dáníẹ́lì |
n. 536 Ṣ.S.K. |
|
Hóséà |
l. 745 Ṣ.S.K. |
|
Jóẹ́lì |
n. 820 Ṣ.S.K. (?) |
|
Ámósì |
n. 804 Ṣ.S.K. |
|
Ọbadáyà |
n. 607 Ṣ.S.K. |
|
Jónà |
n. 844 Ṣ.S.K. |
|
Míkà |
ṣ. 717 Ṣ.S.K. |
|
Nahum |
ṣ. 632 Ṣ.S.K. |
|
Hábákúkù |
n. 628 Ṣ.S.K. (?) |
|
Sefanáyà |
ṣ. 648 Ṣ.S.K. |
|
Hágáì |
520 Ṣ.S.K. |
|
Sekaráyà |
518 Ṣ.S.K. |
|
Málákì |
l. 443 Ṣ.S.K. |
|
Mátíù |
n. 41 S.K. |
|
Máàkù |
n. 60-65 S.K. |
|
Lúùkù |
n. 56-58 S.K. |
|
Àpọ́sítélì Jòhánù |
n. 98 S.K. |
|
Lúùkù |
n. 61 S.K. |
|
Pọ́ọ̀lù |
n. 56 S.K. |
|
Pọ́ọ̀lù |
n. 55 S.K. |
|
Pọ́ọ̀lù |
n. 55 S.K. |
|
Pọ́ọ̀lù |
n. 50-52 S.K. |
|
Pọ́ọ̀lù |
n. 60-61 S.K. |
|
Pọ́ọ̀lùl |
n. 60-61 S.K. |
|
Pọ́ọ̀lù |
n. 60-61 S.K. |
|
Pọ́ọ̀lù |
n. 50 S.K. |
|
Pọ́ọ̀lù |
n. 51 S.K. |
|
Pọ́ọ̀lù |
n. 61-64 S.K. |
|
Pọ́ọ̀lù |
n. 65 S.K. |
|
Pọ́ọ̀lù |
n. 61-64 S.K. |
|
Pọ́ọ̀lù |
n. 60-61 S.K. |
|
Pọ́ọ̀lù |
n. 61 S.K. |
|
Jémíìsì (Àbúrò Jésù) |
ṣ. 62 S.K. |
|
Pétérù |
n. 62-64 S.K. |
|
Pétérù |
n. 64 S.K. |
|
Àpọ́sítélì Jòhánù |
n. 98 S.K. |
|
Àpọ́sítélì Jòhánù |
n. 98 S.K. |
|
Àpọ́sítélì Jòhánù |
n. 98 S.K. |
|
Júúdà (àbúrò Jésù) |
n. 65 S.K. |
|
Àpọ́sítélì Jòhánù |
n. 96 S.K. |
Àkíyèsí: Àwọn ìwé kan wà tí orúkọ àwọn tó kọ ọ́ àti ìgbà tí wọ́n kọ ọ́ tán ò dá wa lójú. Ṣe la fojú díwọ̀n ọ̀pọ̀ nínú àwọn déètì yìí, bí àpẹẹrẹ, àmì l. tó wà níwájú àwọn déètì kan túmọ̀ sí “lẹ́yìn,” ṣ. túmọ̀ sí “ṣáájú,” n. sì túmọ̀ sí “nǹkan bí.”
a Bá a ṣe to àwọn ìwé mẹ́rìndínláàádọ́rin (66) tó wà nínú Bíbélì síbí náà ni wọ́n ṣe tò ó tẹ̀ léra nínú ọ̀pọ̀ ìtumọ̀ Bíbélì. Ọgọ́rùn-ún ọdún kẹrin ni wọ́n ti bẹ̀rẹ̀ sí í tò ó lọ́nà yìí.