ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ July 2024

Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti September 9–​October 6, 2024 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 27

Ní Ìgboyà Bíi Sádókù

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní September 9-15, 2024.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 28

Báwo Lo Ṣe Lè Mọ Ìyàtọ̀ Láàárín Òtítọ́ àti Irọ́?

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní September 16-22, 2024.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 29

Máa Kíyè Sára Kó O Má Bàa Kó Sínú Ìdẹwò

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní September 23-29, 2024.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 30

Àwọn Ẹ̀kọ́ Pàtàkì Tá A Kọ́ Lára Àwọn Ọba Ísírẹ́lì

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní September 30–​October 6, 2024.

Bí Ara Ẹ Ṣe Lè Mọlé Nínú Ìjọ Tuntun

Ọ̀pọ̀ àwọn ará ló ti kó lọ sí ìjọ tuntun tára wọn sì mọlé níbẹ̀. Kí ló mú kí wọ́n ṣàṣeyọrí? Wo ìlànà mẹ́rìn tó lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ tó o bá kó lọ síjọ tuntun.

Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé

Ta ni “obìnrin” tí Àìsáyà 60:1 sọ, báwo ló ṣe “dìde,” tó sì “tan ìmọ́lẹ̀”?