Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Ṣé Gbogbo Àdúrà Ni Ọlọ́run Máa Ń Gbọ́?

Ṣé Gbogbo Àdúrà Ni Ọlọ́run Máa Ń Gbọ́?

Ọlọ́run fẹ́ kí àwọn èèyàn láti gbogbo orílẹ̀-èdè máa gbàdúrà sí òun kí wọ́n lè tipa bẹ́ẹ̀ sún mọ́ òun. Àmọ́, ṣé gbogbo àdúrà ni Ọlọ́run máa ń gbọ́ tó sì máa ń dáhùn?