Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Ẹ̀kọ́ Bíbélì

Bíbélì sọ ohun tó dáa jù tó yẹ ká ṣe nípa àwọn ìbéèrè tó díjú jù lọ láyé. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún sì ni àwọn ìmọ̀ràn rẹ̀ ti wúlò. Abala yìí máa jẹ́ kó o túbọ̀ rí bí Bíbélì ṣe wúlò tó.—2 Tímótì 3:16, 17.

 

Àwọn Ohun Tó Wà

OHUN TÍ BÍBÉLÌ SỌ

Kí Ni Ẹ̀ṣẹ̀?

Ṣé ẹ̀ṣẹ̀ máa ń burú ju ara wọn lọ?

OHUN TÍ BÍBÉLÌ SỌ

Kí Ni Ẹ̀ṣẹ̀?

Ṣé ẹ̀ṣẹ̀ máa ń burú ju ara wọn lọ?

Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Lọ́dọ̀ Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Gbìyànjú Ẹ̀ Wò

Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan lè wá ọ wa láti kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì pẹ̀lú rẹ lọ́fẹ̀ẹ́.

Ṣé O Fẹ́ Ká Wá Ẹ Wá

O lè mọ̀ sí i nípa Bíbélì tàbí àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà.

Ohun Tá A Fi Ń Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì

Lo àwọn ohun tá a fi ń kẹ́kọ̀ọ́ láti kọ́ ohun tó wà nínú Bíbélì. Ó máa jẹ́ kó o gbádùn ìkẹ́kọ̀ọ́ náà, wàá sì rí ìdáhùn tó ń tẹ́ni lọ́rùn sí àwọn ìbéèrè ẹ.

Báwo Ni Bíbélì Ṣe Lè Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́?

Àlàáfíà àti Ayọ̀

Bíbélì ti ran ọ̀pọ̀lọpọ̀ èèyàn lọ́wọ́ láti fara da wàhálà ojoojúmọ́ tó ń bá wọn, ó ti jẹ́ kí ara tù wọ́n, ó sì ti bá wọn mú ẹ̀dùn ọkàn wọn kúrò. Yàtọ̀ síyẹn, ó ti jẹ́ kí ìgbésí ayé wọn nítumọ̀, ó sì ti jẹ́ káyé wọn dáa sí i.

Ìgbàgbọ́ Nínú Ọlọ́run

Ìgbàgbọ́ lè jẹ́ kó o ní ìbàlẹ̀ ọkàn ní báyìí, kó o sì tún ní ìrètí tó dájú fún ọjọ́ ọ̀la.

Ìgbéyàwó àti Ìdílé

Àwọn tó ti ṣègbéyàwó àtàwọn ìdílé máa ń dojú kọ ọ̀pọ̀ ìṣòro. Ìmọ̀ràn tó wà nínú Bíbélì lè mú kí ìdílé rẹ dáa sí i, á sì tún gbé ìdílé rẹ ró.

Ìrànlọ́wọ́ fún Àwọn Ọ̀dọ́

Wo bó o ṣe lè wá ọ̀nà àbáyọ sí àwọn ìṣòro tó ń bá àwọn ọ̀dọ́ fínra.

Eré Ọwọ́ fún Àwọn Ọmọdé

Lo àwọn eré ọwọ́ tó gbádùn mọ́ni tó dá lórí Bíbélì yìí láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa ìwà rere.

Kí Ni Bíbélì Sọ?

Ohun Tí Bíbélì Sọ

Mọ ohun tí Bíbélì sọ nípa àwọn ìbéèrè nípa Ọlọ́run, Jésù, ìdílé, ìjìyà àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.

Àlàyé Àwọn Ẹsẹ Bíbélì

Àwọn ẹsẹ Bíbélì kan wà táwọn èèyàn mọ̀ bí ẹni mowó. Wo ohun tí àwọn ọ̀rọ̀ náà túmọ̀ sí gan-an.

Ìtàn àti Bíbélì

Ka ìtàn tó gbàfiyèsí nípa bí Bíbélì ṣe dọ́wọ́ wa. Ṣàyẹ̀wò ẹ̀rí tó fi hàn pé àwọn ìtàn inú Bíbélì jóòótọ́, wọ́n sì ṣeé gbára lé.

Ìmọ̀ Sáyẹ́ǹsì àti Bíbélì

Ṣé ìmọ̀ sáyẹ́ǹsì bá Bíbélì mu? Máa fi ohun tí Bíbélì sọ wéra pẹ̀lú ìwádìí táwọn onímọ̀ sáyẹ́ǹsì ṣe.