Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

MARCH 15, 2024
ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìròyìn Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2024 #2

Ìròyìn Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2024 #2

Nínú ìròyìn yìí, a máa sọ̀rọ̀ nípa bí Jèhófà Baba wa onífẹ̀ẹ́ ṣe fi hàn pé òun “fẹ́ kí gbogbo èèyàn ronú pìwà dà.” (2 Pét. 3:9) Àá tún rí àtúnṣe tá a ṣe nípa ọ̀nà tá a lè gbà múra tá a bá ń lọ sáwọn ìpàdé àti àpéjọ.