Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Wọ́n Bá Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ṣiṣẹ́

Wọ́n Bá Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ṣiṣẹ́

Báwo tiẹ̀ ló ṣe máa ń rí téèyàn bá ṣiṣẹ́ pọ̀ pẹ̀lú àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà lẹ́nu iṣẹ́ ìkọ́lé? Ẹ gbọ́ ohun táwọn kan tó ti bá wọn ṣiṣẹ́ sọ.