Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Ó Ń Ṣe Wá Bíi Kípàdé Náà Má Parí

Ó Ń Ṣe Wá Bíi Kípàdé Náà Má Parí

Wo fídíò yìí, ó dá lórí àkànṣe Àpéjọ Àgbègbè tó wáyé nílùú Yangon, lórílẹ̀-èdè Myanmar. Ẹ̀rí ńlá làkànṣe Àpéjọ Àgbègbè yẹn jẹ́, pé ojúlówó ẹgbẹ́ ará ni wá, a sì wà níṣọ̀kan lórílẹ̀-èdè táwọn ará ò ti fi bẹ́ẹ̀ láǹfààní láti rí àwọn ará wa látàwọn orílẹ̀-èdè míì fọ́pọ̀ ọdún.