Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Saipan

Ìsọfúnni Ṣókí—Saipan

  • 48,000—Iye àwọn èèyàn
  • 220—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 3—Iye àwọn ìjọ
  • 224—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn Tinútinú—Ní Micronesia

Ó kéré tán ìpèníjà mẹ́ta làwọn tó ti òkèèrè wá sìn ní erékùṣù Pàsífí ìkì sábà máa ń ní. Àmọ́, kí ló ran àwọn àkéde yìí lọ́wọ́?