Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Kosovo

Ìsọfúnni Ṣókí—Kosovo

  • 1,800,000—Iye àwọn èèyàn
  • 240—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 8—Iye àwọn ìjọ
  • 7,792—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

ÌRÍRÍ

Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn Tinútinú—Ní Alibéníà àti Kosovo

Bó tilẹ̀ jẹ́ pé àwọn tó yọ̀ǹda ara wọn yìí kojú ìṣòro, kí ló mú kí wọ́n lè fara dà á?